Ìtàn Nípa Ọgbọn ỌlọrunÀpẹrẹ
Ojẹ Ayàwòrán Isẹ iṣẹdá
Nínú Bíbélì ti oni Ọgbọn ntesiwaju nínú àpèjúwe ará rẹ; Aworan Rẹ, ìwà láàyè ati awọn ìṣẹ́ Rẹ. O nfẹ ìrònú wa sí láti bèrè ibere ti opin àṣàrò àna.
Nisiyi, ẹjẹ ká ṣe aropo gbogbo aami na ni jenesisi, Bíbélì wípé Emi Ọlọrun nrababa lójú ibu kí Ọlọrun tó bẹrẹ sí dá ohun gbogbo sínú ètò ati iwalaye. Ọkàn nínú awọn àmúyẹ Ẹmí Ọlọrun ni Ọgbọn.
Bi ẹ̀mi Àṣẹ Ọlọrun t'in ṣiṣẹ́ ti àgbàrá Rẹ nfi ohùn gbogbo sì ètò, Ọgbọn jẹ ayàwòrán to nṣe àkóso ètò iṣẹ́ Iṣẹdá ³.
Bi ẹdà ti a dá ni aworan Ọlọrun, O wá ni ayé yí láti mú ìtẹ̀síwájú bá iṣẹ iṣẹdá Ọlọrun lati kọ ayé fún ìtùnú ẹdá ènìyàn sugbọn eleyii òní ṣe ṣe láì sí Ọgbọn Ọlọrun.
Kika siwaju: Jẹnẹsisi 1:1-3, Isaiah 11:2, Owe 8:30
Adura: OLÙWÀ, Mọ ṣì ọkan mi páyá fún Ẹmí Ọgbọn Rẹ.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ọgbọn lati Ọrun jẹ ẹbùn Ọlọrun fún wà láti mọ ohun to jẹ ti Ọlọ́run to tọ ati òhún ti o tọ, níní oyè wọn ati gbígbé nípa wọn bi ofin. A ngbe nínú ayé tó kún fún ètò, ayineke, àrékérekè, irọ ati etekete satani, báwò ni wa ṣe lá gbogbo èyí já láì sí Ọgbọn Ọlọrun? Oba Solomoni lẹyin gbogbo ànfàní Ọrọ, Owo, Okiki, Ìmọ, ati irin re nínú itura ayé, ṣe àkòtàn Ọgbọn bi "ìbẹrù Olùwà"
More
A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL