Ìtàn Nípa Ọgbọn ỌlọrunÀpẹrẹ

Ìtàn Nípa Ọgbọn Ọlọrun

Ọjọ́ 3 nínú 7

Idiyelé Ọgbọn

Ọgbọn iwẹ kíkà ati jijẹ ọjọgbọn ni iyẹ lori ṣugbọn Ọgbọn Ọlọrun ko ṣe fi ìyè lè lori bẹni kó ṣe ṣírò níyè. Ọlọrun fi fún wá lati ni abayọri nínú iṣoro, Kiiṣe tori a yẹ tabi pé a gbà nipa ẹkọ.

A gbà wa ni iyanju lati bere fún ngba ti a ba nilo rẹ ¹. A tọka sí Idiyelé Ọgbọn Ọlọrun ni ẹsẹ ìkejì dilogun de Ọkan dilogun ni Bibeli tòní.

Ọgbọn n pàṣẹ fún òwò ati Ọwọ,nipasẹ rẹ ni a nṣe igbekalẹ ọrọ ti kí ntàn; ti a bá nsọ̀rọ nipa ọrọ, o papọ pẹlú orukọ rere ati ododó to nlọ làti ìràn dé ìran Kiiṣe ọrọ tin ṣa.

Awọn àbájáde Ọgbọn ni òye jù wúrà, àní wúrà didan jùlọ ati ohun ìní to darajulo. O San julọ lati ṣe ìlépa Ọgbọn ni ohun to ṣe pataki jù ¹.

Kika siwaju: Jakọbu 1: 5-6, Owe 4:5-9

Adura: OLUWA Ran mi lọwọ láti ri Titobijulo Idiyele Ọgbọn.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 2Ọjọ́ 4

Nípa Ìpèsè yìí

Ìtàn Nípa Ọgbọn Ọlọrun

Ọgbọn lati Ọrun jẹ ẹbùn Ọlọrun fún wà láti mọ ohun to jẹ ti Ọlọ́run to tọ ati òhún ti o tọ, níní oyè wọn ati gbígbé nípa wọn bi ofin. A ngbe nínú ayé tó kún fún ètò, ayineke, àrékérekè, irọ ati etekete satani, báwò ni wa ṣe lá gbogbo èyí já láì sí Ọgbọn Ọlọrun? Oba Solomoni lẹyin gbogbo ànfàní Ọrọ, Owo, Okiki, Ìmọ, ati irin re nínú itura ayé, ṣe àkòtàn Ọgbọn bi "ìbẹrù Olùwà"

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL