Ìtàn Nípa Ọgbọn ỌlọrunÀpẹrẹ
![Ìtàn Nípa Ọgbọn Ọlọrun](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F52847%2F1280x720.jpg&w=3840&q=75)
Ọgbọn wa kí Ọlọrun tó bẹrẹ Iṣẹ Iṣẹdá
Awọn ẹsẹ Bíbélì ti oni tun fún wà ni itẹsiwaju nínú òye nipa Ọgbọn Ọlọrun bí ohun tí o wà níbè kí iṣẹ iṣẹdá Ọlọrun tò bẹrẹ, eleyii mú mi lati máà ro awọn nkán yi;
Pe Ọgbọn jẹ ọrọ ainiye ti ko ni ìgbà, iyi tí Ọlọrun fi ṣe ètò ati igbekalẹ iṣẹ iṣẹdá Rẹ kí O tó bẹrẹ rárá. Eleyii O yatọ sí ohun oniyi àwámárìídìí ati iyalẹnu, papa to bá ni ànfàní lati oju Ọrun Kejì.
Awọn agbami Òkun, awọn Òke gíga, awọn Odò nlá ati kekere pẹlú Okùn awọsanma to yi ayé rogodo ka yíò ma rú ibere na; báwò ni Ọlọrun ṣe ṣe eléyìí?
Kika siwaju: Psalm 8:3,9, 33:6-8
Adura: OLUWA, emi yín Ọ fún titobi iṣẹ ọwọ Rẹ.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
![Ìtàn Nípa Ọgbọn Ọlọrun](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F52847%2F1280x720.jpg&w=3840&q=75)
Ọgbọn lati Ọrun jẹ ẹbùn Ọlọrun fún wà láti mọ ohun to jẹ ti Ọlọ́run to tọ ati òhún ti o tọ, níní oyè wọn ati gbígbé nípa wọn bi ofin. A ngbe nínú ayé tó kún fún ètò, ayineke, àrékérekè, irọ ati etekete satani, báwò ni wa ṣe lá gbogbo èyí já láì sí Ọgbọn Ọlọrun? Oba Solomoni lẹyin gbogbo ànfàní Ọrọ, Owo, Okiki, Ìmọ, ati irin re nínú itura ayé, ṣe àkòtàn Ọgbọn bi "ìbẹrù Olùwà"
More
A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL