Ìtàn Nípa Ọgbọn ỌlọrunÀpẹrẹ

Ìtàn Nípa Ọgbọn Ọlọrun

Ọjọ́ 4 nínú 7

Lati Ayérayé De Ayérayé

Ti a ba nsọ̀rọ nipa Ọgbọn Ọlọrun, o ṣe pàtàkì kí a mọ ohun tí a nsọ̀rọ nipa. Ki nṣe èrò, àṣà tabi iṣe nla to ṣẹ gbòde to nfi ìgbà wá ti a tun fẹ lọ.

Kiiṣe ohun tí a ṣe ni; ti o ti ọwọ eniyan wá tàbí ti ẹdá ènìyàn dá, o ti Ọrun wá ni, O jẹ ọkan nínú àmúyẹ ati iwa Ọlọrun ¹, bi èro Ọlọrun ṣe ri, ìwò Rẹ ati idajọ Rẹ lori ohun gbogbo òsì kọjá ohun tí àrà.

Njẹ èyí yíó jẹ ohun ọwọ lati máà ri, rò nkán ati lati má ṣe ìdájọ́ ni ọnà Ọlọrun ti o dára jù ti ẹdá ènìyàn lọ bi? Eleyii yíò ká fún bi èrò Orun ti wá ni Ọkan rẹ to ati bí o t'in retí ẹ ni ọjọ waju.

Kika siwaju: Aísáyà 55:8-9

Adura: OLUWA, Mo yan lati simi lè Ọgbọn Rẹ.

Ìwé mímọ́

Day 3Day 5

Nípa Ìpèsè yìí

Ìtàn Nípa Ọgbọn Ọlọrun

Ọgbọn lati Ọrun jẹ ẹbùn Ọlọrun fún wà láti mọ ohun to jẹ ti Ọlọ́run to tọ ati òhún ti o tọ, níní oyè wọn ati gbígbé nípa wọn bi ofin. A ngbe nínú ayé tó kún fún ètò, ayineke, àrékérekè, irọ ati etekete satani, báwò ni wa ṣe lá gbogbo èyí já láì sí Ọgbọn Ọlọrun? Oba Solomoni lẹyin gbogbo ànfàní Ọrọ, Owo, Okiki, Ìmọ, ati irin re nínú itura ayé, ṣe àkòtàn Ọgbọn bi "ìbẹrù Olùwà"

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL