Lilépa ÀlàáfíàÀpẹrẹ
Àlàáfíà pèlú Tàtijọ́
Wíwà àlàáfíà pèlú àtijọ́ lè jé ohun ìpèníjà, bóyá o jé ìpinnu tí o kaba mò rè tàbí dídárijì ení tó se búburú sí o. O sé pàtàkì láti f'ara da àtijọ́ kí o máa lé bá ní agbára lórí ìsìnsìyìí tàbí ọjọ́ iwájú. Ronú wòye bí pé ọ ń gún kèké. Tí o bá múra sí wíwò èyín, tàbí o fi afíyèsí rè bà sílẹ̀ ní tààràtà, o máa kùtà lónà ti kò ṣeé yè sílè sínú nǹkan kan. O sé pàtàkì láti máa wò ìwájú àti lówó nínú àwọn ohun títún ti Olórun ń se.
Ònà kan tó ṣe pàtàkì láti wà ní àlàáfíà pèlú àwon ìpalára àtijó ní láti yan ìdaríjì. Nígbà tí o bá dáríjì ẹnìkan tí o palára, kò túmò sí pé o fowó sí ohun tó tí sẹlè. Dípò, o túmò sí pé ọ yàndà ara rè láti tèsíwájú pèlú ayé rè. Àtijó rè tó rẹwà dára fún ohun méjì: láti kékòó àti láti gbádùn ayé tí Ọlọrun fún ni.
Òwe Africa:
Nígbà tí àlàáfíà bá wa ní orílè èdè ìjòyè kò ní láti máa gbé Apata. ~ Òwe Uganda
Àlàáfíà àti ìlàjà ní ìlànà ìwòsàn èyí tí a tí búkún ègbè Tearfund láti jé ara wọn. Níhìn lo wa ìtàn kan láti Rwanda bí ìdaríjì lè wo kódà ìpalára tó jìn jù sàn.
*Ìgbésè:
Ṣe àwọn ipò kan wa tí o nímólárá pé o ń gbé nítorí àìní àlàáfíà? Tí o bá nímọ̀lára brave, forí lé itẹ òkú kán tó wà ní agbègbè rè àti rìn gbà a láti nímólárá ojú ìwòyè nípa àtijọ́. Òpò òkúta ìyè òkú náà ló ní isé òrò ìkẹyìn láti àwọn tó féràn wọn tó n sò “Simi Ní Alaafia”. Fúnra rẹ lákókò láti jẹ́ kí kó sínú ìdẹwò pèlú Olórun àti wà lálàáfíà pèlú ará rè tí o bá ní àbámò tàbí àìnídáríjì nípa àtijó.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ẹgbé̩e̩ Tearfund ńṣe àfẹ́ẹ́rí ìtó̩ni Ọlọ́run nípa bí wọn yóò ṣe jẹ́ abẹnugan ti àlááfíà, ìmúpadà bọ̀ sípò ìbáṣepọ̀ àti àjọṣepọ̀ tí o múná dóko láàrín àwọn ìletò káàkiri àgbáyé. Ẹ̀kọ́ ọlọ́jọ́ méje yìí ní àwọn ìlànà ìṣe fún ìmúpadà bọ̀ sípò àjọ́ṣe rẹ àti gbígbàdúrà fún ayé tí a n gbénú rẹ̀ nípa lílo ọrọ̀ ìjìnlẹ̀ tí n bẹ nínú àwọn òwe ilẹ̀ aláwọ̀ dúdú láti rànwálọ́wọ́ kí abaà leè ṣe àwárí àlááfíà Ọlọ́run tío jẹ́ òtítọ́.
More