Lilépa ÀlàáfíàÀpẹrẹ

Àlàáfíà pèlú Àwon Mìíràn
Ní awọn sóòsì kánkan, ìṣe kan wà tí wọn pé ní pásipárò àlàáfíà èyí tó sàmì ìsókan àti ìfé Kristẹni tí ń ṣàjọpín láàrín àwọn onígbàgbọ. Nígbà tí a bá tè lé àwọn àṣà wọnyìí bá mò wa lára, o lè rọrùn láti gbàgbé ìtúmò tó rẹwà to kún tí mbè léyìn àwọn àṣà yìí. Àgbájọ oókan tó wà láàáfíà, sowing èyí siínú ayé àwọn ẹlòmíràn. Pèlú olúkúlùkù tó gbèrù síi nínú àwọn àwùjọ wa, o dà bí ògiri náà tí ń ga láti gun, gégé bí ọrẹ àti fiféhàn àti àlàáfíà sí àwọn ẹni tí a kò mò.
Pipèsè àlàáfíà sí àwọn mìíràn lè kan rọrùn bí ṣíṣe àbẹwò sí aládùúgbò àgbàlagbà kan, fúnni ní ife omi, fífún àwọn aláìní lóúnjẹ tàbí bíkíta fún ọmọde. O lè jẹ dídárijì ẹnìkan tó tí ṣe télẹ̀, sísorò síta fún àwọn tí a nílára, lilọ kílómítà méjì nígbà tí dípò é o lè má yesè fún íǹsi kàn, tàbí kí o kan sọ pé pèlé. Àwọn isé gbódò jìnlẹ̀ nínú ìgbé ayé ádùrá. Ádùrá fún àlàáfíà tòótọ àti kikó Ìjọba Ọlọ́run lórí ayé yìí.
Òwe Àwọn Africa:
Nígbà tí àlàáfíà bá wa ní orílè èdè, kò ní sí ìdí tí ìjòyè máa fí má gbé Apata. ~ Uganda òwe
Tí ọba bá ní àwọn agbanímọ̀ràn tó dára, àlàáfíà ní ijoba rè. ~ Ashanti proverb
Ègbé Tearfund rí àwọn ìtàn gidi tí ìyípadà àti àlàáfíà kikò. Kà ìtàn alábásisépo Tearfund kan tó ṣe ìrànwó láti fòpin sí inúnibíni ní àgbájọ Nigeria kan.
Ìgbésè:
Ṣe o ní láti wá àlàáfíà nínú ìbáṣepọ̀ pèlú enìkan? Béèrè láti pàdé àti ṣàlàyé ìdí tí o fé se èyí. Bí Olórun láti fi bí wọn ṣe pèsè ìfé àti ìdaríjì bí tí Kristi hàn é.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Ẹgbé̩e̩ Tearfund ńṣe àfẹ́ẹ́rí ìtó̩ni Ọlọ́run nípa bí wọn yóò ṣe jẹ́ abẹnugan ti àlááfíà, ìmúpadà bọ̀ sípò ìbáṣepọ̀ àti àjọṣepọ̀ tí o múná dóko láàrín àwọn ìletò káàkiri àgbáyé. Ẹ̀kọ́ ọlọ́jọ́ méje yìí ní àwọn ìlànà ìṣe fún ìmúpadà bọ̀ sípò àjọ́ṣe rẹ àti gbígbàdúrà fún ayé tí a n gbénú rẹ̀ nípa lílo ọrọ̀ ìjìnlẹ̀ tí n bẹ nínú àwọn òwe ilẹ̀ aláwọ̀ dúdú láti rànwálọ́wọ́ kí abaà leè ṣe àwárí àlááfíà Ọlọ́run tío jẹ́ òtítọ́.
More