Ìmọ̀lára Mímọ́ - Èsì Látinú Bíbélì sí Ìpèníjà GbogboÀpẹrẹ
Òpò ohun láyé yìí lo má ń já wa kúlè. Tí o bá gbà ará e láàyè láti ṣe , o lè fi òpò gbogbo ọjọ́ ayé e máa ronú awon ìjákúlè ti o ti pàdé látàrí ẹnìkan tàbí nǹkan. O rọrùn ki ìjákúlè di àwò ayé wa, látàrí àwọn èèyàn àti àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí kò bá mu ti kò bá àwọn ìrètí wa mu.
Pọ́ọ̀lù Àpọ́sítélì , onkọ̀wé ìwé Róòmù, fún wa ní ònà tó tún dára láti yanjú àwọn ìjákúlè kàkà ki a já wa kúlè! Ohun ti Pọ́ọ̀lù ń fi sùúrù kọ̀ nínú ìwàásù tó se pàtàkì ti inú ìwé mímó ni pé ìjákúlè kò ni àgbàrá láti já o kúlè !. Olórun ti yàn e fún dáradára àti fún àyànmó , torí náà ìjákúlè kò ni àgbàrá láti dáwọ́ aago ohun ti Olórun ti se pà dà sẹ́yìn. Nígbà ti o bá ni ìdààmú ọkàn àti ìrẹ̀wẹ̀sì nítorí àwọn ìjákúlè ojoojúmo nínú ayé, a máa fún ìjákúlè kọ̀ọ̀kan ni àgbàrá púpòju nínú ayé wa. Òkan lára ònà to ga jùlo fún kikọjú àwọn ìjákúlè ni láti fi won si ayè won.
Láti "já-kúlè" túmọ̀ si pé a ti yí àyànmọ́ e padà titi láé......... a ti pè níwọ̀n gbà ti a ti yàn e fún àyànmó àti ìjẹ́pàtàkì àmọ́ ìṣẹ̀lẹ̀ tó jani kúlè tí yí ète àtọ̀runwá e. "Ìjá- kúlè" máa túmọ̀ si pé níwọ̀n ti wón ba ti yàn e àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ kan ti jí iyàn sípò e. Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ojoojúmo ko ni àgbàrá láti já ìpè ti Olórun pè o kúlè !
Pọ́ọ̀lù fún ara Kristi nítọ̀ọ́ni fún ìran tó ń bọ̀, pé ìdáhùn wa si ìjákúlè gbọ́dọ̀ jé ayọ̀ àṣeyọrí àtinú ọkàn. Ẹ̀yà Bíbélì ti King James túmọ̀ esè Bíbélì nípa lílọ òrò ńlá kan, " - a ń máa ṣógo nínú ìpọ́njú, náà ..."
Gbogbo wa lo ti kùnà ! A ti ṣàṣìṣe láti wá gbà gbọ́ pé ìpọ́njú, tàbí àwọn ìjákúlè, won je ìjànbá, pé wọn jẹ ìdíwó tó lè yí ayé ẹni padà, nígbà ti Bíbélì to jé ìtọ́ni wa sínú gbogbo òtító, sò fún wa pé àwọn ìjákúlè ń ṣẹlẹ̀ nígbà to dára jù. O jé àǹfààní fún awa Kristẹni láti fi hàn pé lóòótọ́, , a yàtò àtipe a máa lo àsìkò yìí láti fi ògo ti a ti fi sínú wa. A kò ní sunkún nítorí ìjákúlè , a máa yọ̀ gidigidi nínú ìjákúlè . A kò ní pohùn réré ẹkún látàrí àwọn ìjákúlè, àmọ́ a ń máa wa ọwọ́ ìtẹ̀ka Olórun láti fi ara e hàn.

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ọlọ́run dá ọ Ó sì fi ọ sí àyè tí o wà ní irú àkókò yìí, to love the unlovable, bii àlàáfíà nínú rúkè rúdò, kí o sì fi ayọ̀ tí kò ṣeé dẹ́kun nínú ìṣẹ̀lẹ̀ gbogbo. À ti ṣe bẹ́ẹ̀ lè jọ pé kò ṣeéṣẹ, ṣùgbọ́n o le è ṣeé tí o bá kọ́ oun tí Bíbélì sọ nípa àwọn ìmọ̀lára ọkàn rẹ gẹ́gẹ́ bí ènìyàn àti bí o tilè ṣàkóso wọn. Ètò ẹ̀kọ́ yìí dá lórí àwọn ohun tí a kò kà sí àti nígbà míràn awon ohun ìdojúkọ tí kìí ṣe lásán tí à ń bá pàdé lojojúmọ́, ó sì fún wa ní ìtọ́kasí ẹsẹ̀ Bíbélì láti ṣàkóso ìmọ̀lára wa ní ọ̀nà bíi ti Ọlọ́run.
More
A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Carol McLeod and Just Joy Ministries fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ̀ síi, jọwọ lọsí: www.justjoyministries.com