Ìrìn-àjò HábákúùkùÀpẹrẹ
"Dídúró de Olorun"
Ìfọkànsìn:
Bí Hábákúkù tí tẹ̀síwájú nínú àṣàrò rẹ̀ pe
pẹ̀lú Ọlọ́run, ó dabe ẹni wípé ìbéèrè ń pọ̀ sí í. Nínú ìwé 2, Ọlọ́run fi òtítọ́ kan hàn tí àwọn ènìyàn a máa fojú fò. Ọlọ́run fi ojútùú tí ó rọrùn fún ìṣòro tí ó le, a sì má béèrè àwọn ìbéèrè tí ó lè lọ́wọ́ ọkàn tí ó láròjinlẹ̀ bákan náà.
Ọ̀nà Ọlọ́run tọ́ sì I, torí pé a kò sì sí ní ipele kan náà nínú asiko tàbí ìwàláàyè wá, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà ni a kii mọ ibi tí Ó ń lọ pẹ̀lú ohun tí a ń lá kọjá lọ́wọ́lọ́wọ́. Nígbà mìíràn ẹ̀wẹ̀ a máa jásí wípé Ọlọ́run mọ ohun tí ó ńṣe a sì gbọ́dọ̀ jọ̀wọ́ ìfẹ́ ọkàn wa fún tìrẹ.
Àwọn Ìbéèrè Àṣàrò:
Fi àkókò díẹ̀ ronú sì àwọn ìbéèrè wonyi kí ó tó tesiwaju. Ṣé ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè yí pelu ọkàn tòótọ́ ni ípalẹmọ́ fún èrò Ònkọ̀wé lọ́la.
1. Tẹjú mọ ẹsẹ̀ 1 fún àkókò díè kí ó ronú sì pàtàkì ẹsẹ̀ yii.
Ṣe alààyè èrò rẹ.
2. Báwo ni Ọlọ́run ṣe yàn láti dá Hábákúkù lóhùn, ati wípé kíni ó nsọ fún wá nípa bí ó ṣe yẹ kí a máa gbọ́?
3. Kí ló lérò wípé ó lè jẹ́ ìdí rẹ tí Ọlọ́run ṣe ló ọ̀rọ̀ bí "ègbé" dípò "eégún" nígbà tí ó ń bá Hábákúkù sọ̀rọ̀?
4. Báwo ni a ṣe lè gba èyí sínú ìgbé aiye ojoojúmọ́ wá?

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ètò ẹ̀kọ́ yìí jẹ́ ìrìn-àjò kọjá láàrin àkókò ìpèníjà Hábákúùkù.
More
A fẹ́ dúpẹ lọ́wọ́ Tommy L. Camden II fún ìpèsè ẹ̀kọ́ yìí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ́ kàn sí: http://portcitychurch.org/