Ìrìn-àjò HábákúùkùÀpẹrẹ

Habakkuk's Journey

Ọjọ́ 1 nínú 6

"Pí Pàdé Hábákúkù"

Ìfọkànsìn:
Hábákúkù jẹ́ ìwé tí ó lè tètè rú àìní ìdánilójú sókè ó sì ń pè fún ìrònú. Ìwé náà rọrùn láti pè níjà bákannáà ni o nira láti pè wá níjà. Gẹ́gẹ́ bíi ènìyàn Ọlọ́run lókùnrin àti lóbìnrin, a gbọ́dọ̀ múra tán láti ṣe méjèèjì. Mo mọ̀ pé ó rọrùn fún mí ní kíákíá láti pe ẹlòmíràn níjà, ṣùgbọ́n tí a bá pa idi ọrẹ dà, oun tí ó yá mi lara láti ṣe ni kin jà padà. Ó wá di iṣẹ́ ìsìn sí Ọlọ́run láti gba àwọn ìpèníjà tí Ó tí mú bá ọ fún ìdàgbàsókè re.

Àwọn Ìbéèrè Àṣàrò:
Lo àkókò dí ẹ̀ kí o fi ronú jinlè lórí àwọn ìbéèrè yìí kí o tó tẹ̀ síwájú. Dáhùn wọn pẹ̀lú òtító àti pẹ̀lú àlàyé tó kún ní ìpalẹ̀mọ́ èròńgbà olùkọ ẹ̀kọ́ yìí lóla.

1. Kíni kókó ẹ̀kọ́ tó ní túmọ̀ sí ọ nígbàtí tí o ka Hábákúkù 1?

2. Kíni ohun tí o rò pé ó mú ìwé yìí wọnú àkójọ ìwé Bíbélì (Canon)? Kíni oun tí o rò pé ó jẹ́ èrèdí tí Ọlọ́run ní fún Orí yìí nínú ìwé Hábákúkù?

3. Kíni ohun tí ó jẹ́ gbòógì ní àkókò tí a kọ ìwé yìí?

4. Báwo ni ó ṣe túmọ̀sí fún àkókò tí a wà báyìí?

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 2

Nípa Ìpèsè yìí

Habakkuk's Journey

Ètò ẹ̀kọ́ yìí jẹ́ ìrìn-àjò kọjá láàrin àkókò ìpèníjà Hábákúùkù.

More

A fẹ́ dúpẹ lọ́wọ́ Tommy L. Camden II fún ìpèsè ẹ̀kọ́ yìí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ́ kàn sí: http://portcitychurch.org/