Àìní Àníyàn fún OhunkóhunÀpẹrẹ
Bóyá oókan lára àwọn ìtàn tó tayọ. Tàbí bóyá ìtàn rẹ pẹ̀lú àníyàn yàtọ̀ pátápátá. Àmó èyíkéyìí ìjàkadì tí o bá dojú kọ pèlú àníyàn, Èmí kànna tó jí Kristi dìde kúrò nínú òkú ń gbé nínú ẹ̀. Àti pé Kò fún o ní ẹ̀mí ìbẹrù.
Èyí kò túmọ sí pé tí o mba tiraka pẹ̀lú àníyàn o kò ní ìgbàgbọ tó pọ tó. Kò túmọ sí pé ọ kò jẹ́rìí Olórun tó. Kódà, tí àníyàn bá jẹ́ ohun yen gan-an tó máa ràn é lówó láti kọ́ láti simi le lórí àti nínú Olórun? Njé àníyàn lè jẹ́ ìwúrí láti mú ẹ súnmọ́ Ọlọ́run?
Àníyàn di ẹbùn nígbà tí o bá ràn wa lówó láti sinmi lé Olórun.Kọ̀ túmọ sí pé kí a dáwọ dúró láti wà ìrànlọ́wọ́ tàbí ìrètí. Kò túmọ sí pé a mọ̀ pé ìlépa àlàáfíà dà bíi ìrìn àjò.
Torí náà, njé o ṣeé ṣe láti gbé ní àníyàn lásán? Béèni. Kọ̀ túmọ sí kọ̀ ní sí ohunkóhun tí tí a máa ṣàníyàn nípa. Àmó nítorí Jésù, a lè gbé ní àníyàn lásán kódà tí nǹkan kan bá wà láti ṣàníyàn nípa — kìí ṣe nípa ipá wa àmó nípa iwájú Rè. Ṣe àgbéyèwò àwọn ẹsẹ̀ Bíbélì yìí lẹ́ẹ̀kan sí:
Ẹ máṣe àníyàn ohunkóhun, ṣugbọn nínú ohun gbogbo, nípa àdúrà ati ẹ̀bẹ̀ pẹlu ìdúpẹ́, ẹ máa fi ìbéèrè yín hàn fún Ọlọrun, àti àlàáfíà Olórun tó jù òye ènìyàn ló, yóò pa ọkàn yín àti ẹ̀mí yìn nínú Kristi Jésù. Fílípì 4:6.7 NIV
Fa èémí òtítọ́ sínú. Ọ̀pọ̀ ìgbà ni a ma ń dójú sọ gbólóhùn náà “àlàáfíà,” àmó o sò wípé, “àlàáfíà of Olórun.” a rí àlàáfíà òtítọ nìkan ní iwájú Olórun. Níhìn tí ìdáhùn sí àníyàn kìí ṣe ìdààmú tó dínkù bíkòṣe ọ̀pọ̀ Ọlọ́run?
Gba èyí wò: Ọ̀nà wo ni mo lè gbà láti máa pe ìtẹ̀síwájú àti àlàáfíà Olórun sínú ayé mi?
Gbàdúrà: Olúwa, O ṣeun fún ìwàláàyè Rẹ. Mo wá sọ́dọ̀ Yín lónìí mo ń béèrè fún àlàáfíà tí Ẹ̀yin nìkan lè pèsè. Mo fẹ́ ọ̀pọ̀ Yín síi. Mo pè Yín wa sínú gbogbo ìgbésí ayé mi. E ràn mí lọ́wọ́ láti gbẹ́kẹ̀le Yín ní gbogbo ọ̀nà lónìí. Mo fún Yín ní gbọ gbogbo àwọn àníyàn àti àwọn ìbẹrù. É ràn mi lówó láti má ṣe ṣàníyàn ohunkóhun nípa ìgbẹ́kẹ̀lé tí mo ní nínú Yín. Mo jẹ́rìí Rẹ. Mo fún Yín ní gbogbo emi. Ní orúkọ Jésù’, àmín.
Tí o mba tiraka láti borí àníyàn, tàbí enìkan tí o féràn, ìrànlọ́wọ́ àti ìrètí mbè ní. Kọ́ ẹ̀kọ́ si nípa ohun tí àníyàn lè dá bí, báwo ni o sé le yanjú e, àti báwo ni o sé lẹ ràn àwọn mìíràn tó ń tiraka lọ́wọ́..
Nípa Ìpèsè yìí
Kíni tí ọ̀nà míràn tí ódára jù báwà láti dojú ìjà kọ àwọn àníyàn tí kò lópin tí ó mú ọ ṣe àìsùn? Ìsinmi tòótọ́ wà—ótilẹ̀ lè súnmọ́ ju bí o ti lérò lọ. Fi àláfíà dípò ìjayà pẹ̀lú ètò bíbélì ọlọ́jọ́ méje yí láti ọwọ́ Life.church, tèlé ìfiránṣẹ́ àtẹ̀léra àníyàn fún ohuńkóhun ti àlùfáà Craig Groeschel.
More