Àìní Àníyàn fún OhunkóhunÀpẹrẹ

Anxious For Nothing

Ọjọ́ 5 nínú 7

Njé o nímọ̀lára èbi nítorí o kìí ṣe Kristẹni tí kò ṣàníyàn fún ohunkóhun? Se sí ṣàníyàn fún o ní àníyàn sii nítorí o nímọ̀lára pé kò yé o nímọ̀lára e? Lori wa nínú ọkò kannáà títí dìgbà tóíṣàwarí nǹkan tó yí ohun gbogbo padà.

Ìgbéyàwó mi wà ní rúdurùdu. Mo ń gbè ẹrù iṣẹ́ já lé léjìká mi ti titó àwọn ọmọdé méta, méjì lára wọn tí bàlágà (Olúwa, ràn mí lọ́wọ́!) gbogbo nípa tara mi mi. Ń sisé, didáná oúnjẹ, ṣiṣẹ ìmọ́tótó ilé, didarí, títún nǹkan se, gbigbó búkátà, sísátìlẹ́yìn, ń féràn, pipèsè—gbogbo é wa lórí mi. Àníyàn mi lọ sókè , àti mí kò mò ohun tí mọ máa ṣe nípa e.

Mo gbìyànjú gbogbo ohun tí mọ lè ro: ìmòràn, sàsàrò, lílọ oògùn, orin , eré ìmárale, sí so àwọn ẹsẹ Ìwé Mímó, ìwò sọ orúkọ! Kò s'ohun tó dà bí o ma mú kúrò.Maá sí mi gbó, O dájú pé o ràn mí lówó láti ṣe àwọn nǹkan wọnyìí. Mo kó láti lọ àwọn ohun èlò tí nílò láti mú ara mi simi lórí Kristi léèkan sí. Àmó mo yin tiraka. Wò eyìn wo, ohun kan tí mo rí pé mi kò gbìyànjú ni “má gbìyànjú.”

Tí o bá ṣàwarí Ìwé Mímó, wa rí a òpò ẹsẹ nípa ìdààmú.Mo mò nítorí mo ń wà ìlànà ajẹ́bíidán láti ràn mí lówó láti borí lẹ́ẹ̀kan láìtún tún un ṣe. Nínú ṣàwarí mi, Mo rí ohun àìròtélè . O ní láti fiyè sí í láti rí i, àmó nínú àwọn ẹsẹ yìí ìtóni kíkún látodò Bàbá wa láti má ṣe nǹkan kan. Béèni, gidigidi—kò sí ohunkóhun.

Ni Mátíù 11:28 NIV, Jésù sò wípé, " é wá sódò mi, gbogbo àwọn tín sàárẹ̀ àti àwọn tín rù ẹrù ìnira , àti Èmi yóò fún yín ní ìsimi .” Òun lọ ń sisé níbi, kìí ṣe awa. A kan ní láti wá sódò Rè.

Ní Jòhánù 14:27 NIV, O sò wípé, “ Àlàáfíà ní mo fí sílè pèlú yín; àlàáfíà mi Mo fífún yín …” Se o ń nímọ̀lára kókó òrò? O ń fún wa ní àlàáfíà, O fún wa ní ìsimi. A kò sè ohunkóhun.

Léèkan sí i Ní Mátíù 6:25-34 NIV, ẹsẹ Bíbélì tó lókíkí sò fún wa pé kí a má ṣe ṣàníyàn, nítorí kódà Olórun máà “wọ̀ koríko pápá láṣọ,”,” mélòmelò ní O tọju wa? A tí sọ fún wa pé“ kí a wá ìjọba Rè náà… àtipe gbogbo àwọn nǹkan wọnyìí ni a yóò” fún wa. Ìyẹn ọ̀tún—se o gbámú? Fífún wa!

Olúfúnni ní Olórun. O ní ìdáhùn, àti O ń sátìlẹ́yìn wa. Àwọn nǹkan kan tí a kò lè ṣe fún ara wa, àmó bẹẹ gan ní Òun se see. Fún wa láti nílò Rè.

Gbogbo ohun tí mọ ṣàníyàn nípa ṣíṣe jáde dáradára ni ònà kan tàbí mìíràn. Kìí ṣe títí dígbà tí mo mí kanlè , mo simi, mo tó Jésù wá tòótọ, dákẹ́ jẹ́ẹ́, mo jòwó ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé , sò fún Olórun pé mo gbẹ́kẹ̀lẹ́ É pátápátá— àti nígbà náà mo kó láti má ṣe ohunkóhun — tí mo rí àlàáfíà nígbèyìn. Níkẹyìn, ádùrá mi dikùn nípa ipò mi àti òpò nípa gbígbẹ́kẹ̀lẹ́ mi nínú E.

Tí o bá má ní láti ṣe bẹẹ, mo níṣìírí gan láti simi nínú Rè. O lè gbẹ́kẹ̀lẹ́ E. Níhìn ní ádùrá ti mon gbà nígbà tí mo bá tún nímọ̀lára pipòrúurùu látówo àníyàn:

Olúwa Ọ̀wọ́n,

Mo tó Yín wá lónìí láti bèèrè fún ìrànlọ́wọ́ Yín. Eyìn ní gbogbo ohun mi. Olúwa,Mo nílò àlàáfíà. Mo fún Yín ní àníyàn mi. É gbà Olúwa. Mo gbà àlàáfíà, ìfé àti òye Yín. É ràn mí lọ́wọ́ láti yípadà sí Yín kìí se sí ara mi. É ràn mí lówó láti dẹkùn ṣiṣẹ àti bèrè sí ní gbékèlé Yín. É ràn mí lówó láti wait de ìdáhùn Yín, nítorí mo mò pé wọn dára. É fún mi ní ogbón, ìrètí àti àlàáfíà. É ṣeun, Olúwa fún sùúrù àti oore ọ̀fẹ́ Yín. Mo féràn Yín, Mo mọ̀ pé É féràn mi púpò kọjá béẹ̀ jù bí mo lè tí lèé lo.

-Lori

Ọjọ́ 4Ọjọ́ 6

Nípa Ìpèsè yìí

Anxious For Nothing

Kíni tí ọ̀nà míràn tí ódára jù báwà láti dojú ìjà kọ àwọn àníyàn tí kò lópin tí ó mú ọ ṣe àìsùn? Ìsinmi tòótọ́ wà—ótilẹ̀ lè súnmọ́ ju bí o ti lérò lọ. Fi àláfíà dípò ìjayà pẹ̀lú ètò bíbélì ọlọ́jọ́ méje yí láti ọwọ́ Life.church, tèlé ìfiránṣẹ́ àtẹ̀léra àníyàn fún ohuńkóhun ti àlùfáà Craig Groeschel.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ìjọ Life.Church fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé die síi, jọ̀wọ́ lọ sí https://www.life.church/

Awọn Ètò tó Jẹmọ́ọ