Lilépa KáróòtìÀpẹrẹ

Chasing Carrots

Ọjọ́ 7 nínú 7

Lílépa Ọlọ́run

Níbo ló ń lọ?

Ìbikíbi tí o ń lọ nígbàkigbà, ó rán ni lọ́wọ́ lati ní èbúté lọ́kàn.

Ìṣòro pẹ̀lú ayé tó yí wa ká, àmọ́, ni pé a dojú kò wá pẹ̀lú àwọn ohun tí ó yẹ kí a ṣe. Ó yẹ kí a lépa òkìkí àti àfọwọ́si àti ohun gbogbo mìíràn. Pẹ̀lú àwọn òpò èbúté tó ń bọ̀ níwájú wa, kò yà ní lẹ́nu pé mélòó nínú wá lọ wà ní ìyàlẹ́nu, tọ́ ń wá ìtọ́sọ́nà ní ayé.

Tí a bá lágbára láti máa lọ síhà èbúté kan lákòókò kan, kí ni kí èbúté náà jé?

Hébérù 12:1-3 fi ìyẹn hàn kedere pé. Ó yẹ kí a tẹjú mọ́ Jésù. Nígbà tí a sáre sọ́dọ̀ Rè, a kò jèrè Òun nìkan, àmọ́ gbogbo ohun mìíràn tí a nílò. Ó san ìjìyà fún àwọn ẹsẹ wá. O mú ìyè àìnípẹ̀kun wá fún wa. Ó pèsè fún wa lọ́jòojúmọ́. Atipe Ó yí wa padà láti dí àwọn ènìyàn tí a dà wa láti jé.

Àmọ́ báwo ni a ṣe lè sáré lọ síhà Kristi? Se ohun ti O se.

Àdúrà. nígbà tí Jésù ni láti sọ agbára Rè dọ̀tun lẹ́yìn ìgbà Tọ́ lọ́jọ́ tó ń bá àwọn èrò náà sọ̀rọ̀, Ó wà Bàbá Rè. Nígbà tí Ó wá nídààmú lógbà Gẹtisémánì, O kígbe lóhùn rara si Bàbá Rẹ̀. Àdúrà mú wá sopo mò Kristi.

Ènìyàn. A sedà wa láti gbé ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn ẹlòmíràn. Jésù yí ara Rè ká pẹ̀lú àwọn ènìyàn jákèjádò àkókò Rè níbi, Ó ń pẹ́ wọn níjà àti fún wón ní ìsírí nínú ìgbàgbọ́. O see ṣe kí o lépa ohunkóhun tí àwọn tó ń lọ àkókò pẹ̀lú jù lọ ń lépa. Nígbà náà, lọ àkókò pẹ̀lú àwọn ènìyàn tó ń lépa Ọlọ́run.

Sìnsìn. Jésù wá sáyé láti sìn—O so fún ara Rẹ̀. O se bẹẹ ni ọ̀nà tó tóbi àti tó kéré, àti pé Ó parí isé òjíṣẹ́ Rè pẹ̀lú iṣẹ́ ìsìn nígbẹ̀yìngbẹ́yín— Ọ́ fi ẹ̀mí Rè rọ́pò fún tí wa. Nígbà tí a bá sìn àwọn tó wá láyìíká wa a ń lépa Ọlọ́run nípa ṣíṣe ohun tí Jésù ṣe.

Ààwẹ̀ Gbígbà. Bóyá Jésù ń gbà ààwẹè láti sàìfenu kan oúnjẹ nínú aginjù, tàbí láti yẹra fún àkókò pẹ̀lú àwọn ènìyàn nígbà tí Ọ́ lọ kúrò láti wá ìpàrọ́rọ́ àti dídá wà, Jésù, ọmọ Ọlọ́run, mò pàápàá pé Òun nílò láti yọ àwọn nǹkan kan kúrò fúngbà díè nínú ayé Rè láti lẹ́pa Ọlọ́run. Kí ni o lè yọ kúrò lẹ́kọ̀ọ́kan láti lépa Ọlọ́run?

Ọ̀rọ̀. Jésù kúkú bèrè sí í lórí èyí—bí Jòhánù, ṣé sọ, Kristi ní ọ̀rọ̀ Ọlọ́run gan-an ní ìrísí ènìyàn. Oókan lára ònà tó dára jù tí a lè fi mọ Kristi ní lílọ àkọ́kọò ni kíkà, ṣíṣàsàrò àti ìjíròrò lórí ìtọ́sọ́nà Ọlọ́run fún wa nínú Bíbélì dédé.

Ìṣe: Èwo nínú àwọn tòkè yìí ni ìwọ yóò gbé ìgbése lé lórí nínú ayé rè? Báwo ni wà se bẹ̀rẹ̀? Ta ní ìwọ yóò sọ fún nípa e?

Díè sí nípa lílépa Ọlọ́run.

Ọjọ́ 6

Nípa Ìpèsè yìí

Chasing Carrots

Gbogbo wá ló ǹ lépa nǹkan kan.O sábà máa ń jẹ́ nǹkan tí kò sí lárọ́wọ́tó bíi—iṣẹ́ tó dára, ilé tó tún dára,ìdílé pípé, àfọwọ́sí àwọn ẹlòmíràn. Àmó ńjẹ́ èyí kì í múni se àárẹ̀? See kò sí ọ̀nà mìíràn tó dára ni? Ṣe ìwádìí nínú ètò Bíbélì titun tí Life.Church, tí ń tè lé onírúurú ìwàásù Pastor Craig Groeschel nípa, lílépa kárọ́ọ̀tì.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ìjọ Life.Church fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé die síi, jọ̀wọ́ lọ sí https://www.life.church/