Lilépa KáróòtìÀpẹrẹ
Lílépa lrọ̀rùn
Bóyá ó ti sú wa a ṣá wa lọgbẹ́, a dáwà, tàbí ó tojú súwa, gbogbo wa náà ni a máa ńbá ra wa ní àkóko lílépa ìrọ̀rùn. Ta ni ẹni tí kò i tíì náwò kọjá àyè, jẹ àjẹjù, sun àsùn piyè, mu àmujù, àti pọ́nlé ju bóṣeyẹlọ ohun kan láti fún wa ní ìrọ̀rùn?
Ìtàn ọ̀rọ̀ tíó ńjé̩ ìrọ̀rùn ṣe wọ́rọ́kọ́, a múu jàde láti inú ọ̀rọ̀ Látìnì méjìcom éyí tí ó tù mọ̀ sí lápapọ̀ pẹ̀lú" àti fortis tí ó túmọ̀ si ò lágbara tàbi ìkì nínú "Lé̩yìn èyí, ọ̀rọ̀latini náàconfortaretúmọ̀sí láti fi ọ̀pọ̀lọpò̩ agbára fún ni. Nígbà tóyá, ọ̀rọ̀ Faransé, conforter, fi ọ̀rọ̀ bíi "ìgbọ́kànlé" àti "ìrànlọ́wọ́" kún ìtumọ̀ náà. Ní ìwọ̀n ọdún okòólélé̩gbẹ̀ta ọdún sẹ́yìn, ọ̀rọ̀ Faransé míràncomfortenni atúmọ̀ sí " láti túraká, bákẹ̀dùn. Níìparí, nígbà tó di okòólélọ́ọ̀dúrún ọdún sẹ́yìn, ọ̀rọ̀ yìí ní èdè òyìnbó bẹ̀rẹ̀ sí túmọ̀ sí ìrọ̀rùn nípa tara té a ní òye rẹ̀ lónìí.
Kílódé tí eléyìí ṣe ṣe pàtàkì? Ní ìwọ̀n bíi ọdún ẹgbẹ̀rún, ọ̀rọ̀ náà "ìrọ̀rùn" yé padà láti "agbára àpapọ̀," sí "adérora lọ́wọ́."
Njé̩ orí Ọló̩run bíi agbára rẹ, nínú ìrora pẹ̀lú rẹ, tàbí Olùdánisí kúrò nínú ìrora?
Wòlíì Isaiah sọtẹ́lẹ̀ nípa Mèsáyà kan tí yóò wọnú ayé wa wá láti wá gbọgbẹ́ fún àiṣedédè wa àti jẹ̀yà fún ìwòsàn wa.Tóbá jé̩ pé ìṣẹ̀dá ìgbàgbó̩ wa ni wípè kí á rìn ní ipasẹ̀ Jésù, ẹ jẹ́ ká wo ìdàhùn rẹ̀ nípa ìrora. Nínú Pétérù kínní orí kejì ẹsẹ̀ kọnkànlélógún dé karùndínlọ́gbọ̀n, a rí Olùgbàlà tí ó gba ìrora ní ìdákẹ́jẹ́ bí o jé̩pé kò tọ́ síi. Jésù kò yẹra fún ìrora tàbí tìí sí elòmíràn, Óun wá sí ayé wa ósì sọ ìrora wa di tirẹ̀
Jésù ni àpapọ̀ agbára. Lẹ́yìn náà kí ó tó padà sí ọ̀dọ̀ Baba, Ó ṣeìlérí fún wa pé Ẹ̀mí míńó̩-"Olùtùnú"-kìí ṣe pé yóò pẹ̀lú wa nìkan, ṣùgbó̩nnínúwa! Eléyìí jẹ́ ohun tó tó lèpa.
Nítorí náà, ẹ má jé̩ lèpa ìrọ̀rùn ayé yìí bíi erè amóhùnmáwòrán Netflixpẹ̀lú awọn ọ̀ré̩ bíi Ben àti Jerry. Yàlà èyí ẹjẹ̀ ká lépa ìtùnú ti Ẹ̀mí mímọ́, ké a sìmọ̀ pé kò túmọ̀ sí pé ìgbé ayé tí kò ni ìrora nínú ṣùgbó̩n ìtùnú láàrín ìrora.
GbàdúràỌlọ́run, n ó fẹ́ ìrora, ṣùgbó̩n mo fẹ́ ọ. Jò̩wọ́ yí òye mi nípa ìrọ̀rùn rẹ. padà, ràn mí ló̩wó̩ láti mọ̀ ní ara. Ẹ̀mí mímọ́ fi hàn mé bí "àkọ́jọpọ̀ agbára" ti wà pẹ̀lú mi áti nínú mi. Jésù, o ṣeun pé oru ìtìjú mi lórí àgbélèbú. Àmín
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Gbogbo wá ló ǹ lépa nǹkan kan.O sábà máa ń jẹ́ nǹkan tí kò sí lárọ́wọ́tó bíi—iṣẹ́ tó dára, ilé tó tún dára,ìdílé pípé, àfọwọ́sí àwọn ẹlòmíràn. Àmó ńjẹ́ èyí kì í múni se àárẹ̀? See kò sí ọ̀nà mìíràn tó dára ni? Ṣe ìwádìí nínú ètò Bíbélì titun tí Life.Church, tí ń tè lé onírúurú ìwàásù Pastor Craig Groeschel nípa, lílépa kárọ́ọ̀tì.
More