Lilépa KáróòtìÀpẹrẹ
Lílépa ìtẹ́wọ́gbà
Èyíni ohun kan ná: ìtẹ́wọ́gbà jẹ́ ohun tí a gbọ́dọ́ ṣe afẹ́ẹ́rí, ẹ máa bá wa kálọ, èyí kìí ṣe ìtan ni jẹ
Ìtẹ́wọ́gbà jẹ́ ohun tí a gbọ́dọ́ ṣe afẹ́ẹ́rí, Ṣùgbọ́n ohun tí ó leé tún niṣe tàbí banijẹ́ ni ìtẹ́wọ́gbà ẹni tí o n ṣe afẹ́ẹ́rí rẹ̀.
A kàn tilẹ̀ ti dá wa láti ṣe afẹ́ẹ́rí ènìyàn. Gẹ́gẹ́ bí ọmọdé àwọn àgbà a máa yìn wà nígbà tí a bá ṣe ohun tí ó dára. A gbádùn ìforì yìn wọn, a yóò sò sì tẹ̀ síwájú láti máa ṣe ohun tí ó dára. Ní ilé ìwé a máa nkẹ́kọ̀ọ́ taratara láti ṣe àwárí oríyììń lọ́wó̩ àwọn. Olùkọ́ tàbí kí á ṣe àṣìṣe láti rí ìtẹ́wọ́gbà lọ́wó̩ àwọn ẹlẹgbẹ́ wa. Tí a bá sì sìti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ a màa ńlo ọ̀pọ̀lọpọ̀ wákàtí lẹ́nu iṣẹ́ ní ìrètí ṣe ìwúrí fún àwọn ọ̀gá wa, tàbí kí ára ilé ńlá tàbí ọkọ̀ tó dára lá ti gba sàdánkátà lọ́wọ́ àwọn ọ̀rẹ́ tàbí ẹbí.
Tí a bá sì ṣe àṣeyọ rí nínu gbígba ìtẹ́wọ́gbà lọ́wọ́ ènìyàn, àádà bí i ẹni ńlá. Ayé a mọ́lẹ̀ síi, yóò dàbí ẹni pé àgbéré wà látẹ́lẹsẹ̀ wa, ìdiwọ̀n ara eni yóó gbéwọ̀n síi.
Ṣùgbọ́n
O mọ̀ wípé ṣùgbọ́n kan yoo wà.
Lẹ́yínwá àṣẹ̀yìn bọ̀ ò̩kan nínú wọn yoo kùnà láti sẹ ìtẹ́wọ́gbà rẹ tí èyí bá ṣẹ lẹ̀ yoo burú jù. O tilẹ̀ lè ti mọ èyí.
Kìí ṣe pé o n wo jú àwọn ènìyàn búburú. O kò tilẹ̀ le è rí ìtẹ́wọ́gbà tí o ní lò lọ́wó̩ ènìyàn. Ọlọ́run nìkan ni ó le è sọ bí fífẹ́ ìtẹ́wọ́gbà rẹ ṣe jin lẹ̀ sí, àti pe mọ èyí, O kò ní lò láti fi orí rẹ dúro tàbí se bá kan lá ti jèrè ìtẹ́wọ́gbà rẹ̀. Ní wọ̀ngbà tí o bá gba krístì ní Ọlùgbàlà rẹ tí o sì fi ṣe Olúwa ayé rẹ o ti di ìtẹ́wọ́gbà látọ wọ́ O̩lọ́run. Bó ṣe rí nìyí. O ti ṣe tán, nítorí láti ibí yìí o ti di ọmọ Ọlọ́run.
Ó ṣeé ṣe kí o ti gbọ́ àwọn ǹkan wọ̀nyí rí. Lónìí, jẹ́kí ó wọ akínyẹmí araà rẹ. O ní gbogbo àṣẹ tí o lè nílò—àṣẹ tí kò lè yẹ̀ láíláí. A ti fi èdìdí lé iyeè rẹ, o sì lè sinmi nínú àṣẹ Ọlọ́run Baba rẹ.
Gba èyí rò: Ènìyàn tàbí ǹkan wo lo gbójúlè fún àṣẹ? Báwo ni àwọn ìbáṣepọ̀ rẹ yóò ti yí padà tí o bá gba àṣẹ Ọlọ́run láàyè láti bá àìní yìí pàdé?
Nípa Ìpèsè yìí
Gbogbo wá ló ǹ lépa nǹkan kan.O sábà máa ń jẹ́ nǹkan tí kò sí lárọ́wọ́tó bíi—iṣẹ́ tó dára, ilé tó tún dára,ìdílé pípé, àfọwọ́sí àwọn ẹlòmíràn. Àmó ńjẹ́ èyí kì í múni se àárẹ̀? See kò sí ọ̀nà mìíràn tó dára ni? Ṣe ìwádìí nínú ètò Bíbélì titun tí Life.Church, tí ń tè lé onírúurú ìwàásù Pastor Craig Groeschel nípa, lílépa kárọ́ọ̀tì.
More