Lilépa KáróòtìÀpẹrẹ

Chasing Carrots

Ọjọ́ 4 nínú 7

Lílépa Ìjépípé

“E jé pípé, nítorí náà, bí Baba yín tí òrun ṣé jé pípé” Mátìú 5:48

Kò sí nǹkan bàbàrà ńbẹ̀, sebi. Ó kàn yé kí o jé pípé bí Olórun mímó, òlódodo tí gbogbo àgbáyé se jé pípé

Kò sí nǹkan bàbàrà ńbẹ̀, sebi

Bẹ́ẹ̀nì, kìí se púpò.

Tí o bá lè mú ara rè jé pípé, níbo ní o máa tí bèrè gan? Olórun jé pípé nítórí kò sí èsè, tàbí ìwà àìtó, tó ńbẹ̀ nínú Rè. A kò sòrò nípa àwon èrò ayé tí ìjépípé níbi—àwon àso pípé, ilé pípé, ọkọ tàbí aya pípé. Ohun tí a ń sò nípa jù ìyẹn lo gidi-gan. O máa ní láti jé aláìlésè. Kò sí ìro pípa, kò sí èpè síse, kò sí títàka sí àwon omo, tàbí “yíyá” ọ̀rọ̀ aṣínà tí Netflix òré rè.

Jé kí a se bíi pe o sò pé "dájúdájú. Mo lè se. Àtipe o dé ṣé. Ó yí ìwà búburú rè padà, o ṣègbọràn sí àwọn òfin ìrìnnà ìsáré. O fífún àwon aláìní, o san-wó Netflix fún ara rè. Àtipe o se èyí fún ojó, nígbà náà òsè, nígbà náà òsú, nígbà náà òdun.

Síbè o kò lè jé pípé

Wò, àwon òràn èsè kékeré yí wà tí o tí dá télè. Bíi Jákọ́bù 2:10 we sò—tí o bá pa gbogbo òfin nínú òrò Olórun, àmó kùnà léèkánsoso, o yí wà lórí ìkó.

Nítorí náà, níbo lo fé lo láti ibí?

Nínú Màtíú 19, odomode ọkùnrin rí pẹé òun fẹẹ́ ṣé dáadáa sí. Ó bèèrè lówó Jésù pé kíni o yé kí òun se láti ní ìyè àìnípẹ̀kun. Jésù sò fún láti ṣègbọràn sí lájorí àwọn òfin. Odomode ọkùnrin náà sò wipé òun tí pa ọ̀kọ̀ọ̀kan lára àwon òfin yen mò. Nígbà náà, Jésù dáhùn, “tí o bá fé jé pípé, lo, tá gbogbo ohun ìní rè àti fún wón àwon tálákà, àti pé ìwọ yóò ìṣúra ní ọ̀run. Nígbà náà wá kí o sì, tèlé mi.” Àmó nígbà tí gbò èyí, ó kúrò níbè pẹ̀lú ìbánuje, nítorí o ní òpò ọ̀rọ̀.

Jésù kò sọ fún odomode okunrin pé dídì pípé kìí se ètò ígbèsè méjì. Àkọ́kọ́, ṣègbọràn sí àwọn òfin the commandments, àti èkejì, fúnni ní gbogbo ohun ìní rè. Jésù ń sọ pé ipá ọ̀nà sì ìjẹ́pípé bèrè pẹ̀lú pipále mọ́ ohunkóhun tí ó lè dènà ẹnì láti tè lẹ́ E.

Àmó ìjépípé? Báwo ní eníkeni lè jé pípé? Èyí kìi se ìru ìjépípé tí ayé. O dára gidi-ga ní. Nígbà tí o yàn láti tè lé Kristi, O bo àwon èsè rè àti àìpé rè pèlú ikú tó kú lórí àgbélébùú. Àtipe ní ojú Ọlọ́run, wá jẹ́ pípé ní gbogbo ònà gege bí Kristi fúnra Rẹ̀.

Àdúrà: Olórun, mo dúpé lówó Yín fún ebo omo Yìn. E ràn mi lówó láti jà ara mi gbà lówó ohunkóhun tó ń sèdíwó fún mi láti máa tè lé Kristi Kristi.Ní Orúko Jésù ’, Àmín.

Ọjọ́ 3Ọjọ́ 5

Nípa Ìpèsè yìí

Chasing Carrots

Gbogbo wá ló ǹ lépa nǹkan kan.O sábà máa ń jẹ́ nǹkan tí kò sí lárọ́wọ́tó bíi—iṣẹ́ tó dára, ilé tó tún dára,ìdílé pípé, àfọwọ́sí àwọn ẹlòmíràn. Àmó ńjẹ́ èyí kì í múni se àárẹ̀? See kò sí ọ̀nà mìíràn tó dára ni? Ṣe ìwádìí nínú ètò Bíbélì titun tí Life.Church, tí ń tè lé onírúurú ìwàásù Pastor Craig Groeschel nípa, lílépa kárọ́ọ̀tì.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ìjọ Life.Church fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé die síi, jọ̀wọ́ lọ sí https://www.life.church/