Lilépa KáróòtìÀpẹrẹ
Lilépa Kárótì
Èrò lilépa kárótì wá láti inú àfiwé kárótì ati òpá tí a kọ́kọ́ kọ nípa rẹ̀ láàárín odún -1800s. Fojú inú wo àwóràn omodé kan ti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ pèlú kárótì tó ñ se dirodiro tí kò sì sí ní àrọ́wọ́tó ẹranko náà. Elésin náà mú káàrótì sórí òpá tó gùn láti lè mú kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà sáré.Fún kétékété náà donkey,the nígbà gbogbo ní èrè náà má wa ní ìgbésè kan.
Bóyá ìwọ gan máa ń rí araà rẹ bíi kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ yii?
Lọ́pọ̀ ọdún sẹ́yìn ṣáájú odún 1800, Oba Sólómónì dárò lórí ìlépa òtúbáńtẹ́ ní ayé gégé bi àsán “ìlépa aféfé.”
Ṣé o tí gbínyànjú láti mú aféfé rí? Ìgbésè kan ló máa ń kù nígbà gbogbo.
Ohun èké tó wa nípa “ ìgbésé kan lo ku” ní pé ìgbà gbogbo ní ìgbésé kan máa ń kù. Lẹ́yìn ọdún díẹ̀ sií péré lórí iṣẹ́ yìí, tàbí nígbà tí mó bá kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nílé ẹ̀kọ́ gíga, gbàrà tí o bá ṣègbéyàwó, tàbí nígbà tí àwọn ọmọ bá dàgbà, nígbà tí ìgbágbò rè bá tí lokun síi, tàbí nígbà tí o lè rà ohun tó kan tó sélérí ayó. Ìgbésè. Kàn. Soso. Péré.
Ònà tó dára ju èyí wa láti gbé ayéè rẹ, ò bá fún araà rẹ ní ìsinmi, ọ̀pọ̀ mbé nípa ayé jú ǹkan títóbi àti àwọn ǹkan tó dára lọ
Jésù sọ̀rọ̀ sí àwon amẹ́mìígbóná síi ní Mátìú 6. Bí o ti ń kà òrò Jésù lónìí,gbíyànjù láti ṣe èyí. Mí kanlè kí ó sì mú gbogbo ìbìkítà kúrò lọ́kàn rè.Fojúnú wò pé o wá níbe bí O tín kọ́ni. Kíni o jókòó lé? Báwo ní òórùn atégún náà ti rí? Báwo ní ìró ohùn Rè sé rí? Kí ni ohun mìíràn tí o ń gbò? Kí no o rí? Kí lo ń han kedere nínú rè sí ìró ohùn Rè?
Léyìn tí o bá tí kà Ìwé Mímó tónìí pèlú?
Gbàdúrà: Lèyín kikà àwon ìwé mímó tónìí, gbàdúrà kí o sì béèrè lọ́wọ́ Ọlọ́run fún ìrànwọ́ láti lè dẹwọ́ díẹ̀ láti lè gbọ́ ohùn Rẹ̀ ní gbogbo ìgbà.
Lọ sí ‘àwọn fídíò, àwon ìjíròrò ìtósánà, àti pùpó síi nípa Lilépa Kárótì.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Gbogbo wá ló ǹ lépa nǹkan kan.O sábà máa ń jẹ́ nǹkan tí kò sí lárọ́wọ́tó bíi—iṣẹ́ tó dára, ilé tó tún dára,ìdílé pípé, àfọwọ́sí àwọn ẹlòmíràn. Àmó ńjẹ́ èyí kì í múni se àárẹ̀? See kò sí ọ̀nà mìíràn tó dára ni? Ṣe ìwádìí nínú ètò Bíbélì titun tí Life.Church, tí ń tè lé onírúurú ìwàásù Pastor Craig Groeschel nípa, lílépa kárọ́ọ̀tì.
More