Àwọn Ìlànà Àńtẹ̀ẹ̀lé Fún Ìmójútó Àkókò Láti Inú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́runÀpẹrẹ
Se eto ojo kokan
Se eto ojo kokan
ọlọgbọ́n
#It’s no secret that to be successful with your finances, you must plan where you will spend your money before it winds up in your bank account. We should take the same disciplined approach to our time. After all, unlike money, we can’t earn more time, so we should be even more inclined to budget our hours than our dollars.
Ki ise asiri lati se aseyori pelu eto isuna re, o gbodo seto ibi ti o ma na owo re si ki o to fe danu kuro ninu iwe akosile ileifowopamosi re. A gbodo mu igbese iseraeni kan na si akoko wa. Lehin gbogbo re, yato si owo, a ko le ni akoko si, tori eyi, a gbodo le wa gere lati fasehin ju si eto isuna awon wakati ju awon owo.
If you followed Jesus’ lead in day two of this reading plan, you should have clear boundaries outlining how much time you have dedicated to be productive in a given day. With these boundaries set,.... your commitments collected, and your essential few projects and tasks identified, it’s time to enter into a more granular planning mode, determining how you are going to spend each hour of each day. I love Jesus’ words in Luke 14:28: “For which of you, wanting to build a tower, doesn’t first sit down and calculate the cost to see if he has enough to complete it?” The way we “calculate the cost” of our productive activities is by budgeting our time, ensuring we have “enough to complete” the things we have committed to.
Bi o ba tele itoni Jesu ninu ojo keji eto kika yi, oo ni eto gbendeke to mo gara iye akoko ti o ti ya soto lati wulo ninu ojo ti a fi fun o. Pelu awon ila sile gbendeke......
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ṣé ó t'ojú sú ọ pé kò sí ju wákàtí mẹ́rinlélógún lọ nínú ọjọ́? Gbogbo ǹkan di ìkàyà fún ọ nítorí oye àwọn iṣẹ́-àkànṣe tó yẹ kí o ṣe? Ṣe ó sú ọ pé gbogbo ìgbà ni ó maá ń rẹ̀tí o kò sì ní àkókò tó láti lò nínú Ọrọ̀-Ọlọ́run àti pẹlú àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí rẹ? Eléyìí lè jẹ́ ìdojúkọ tí ó wọ́pọ̀ jù l'áyé. Ìròyìn ayọ̀ ibẹ̀ ni wípé Bíbélì fún wa ní àwọn ìlànà tí a lè lò láti ṣ'èkáwọ́ àkókò wa dáadáa. Ètò-ẹ̀kọ́ yìí yíó fẹ àwọn Ìwé-mímọ́ wọ̀nyí l'ójú yíó sì fún ọ ní àwọn ìmọ̀ràn tí ó wúlò fún bí wàá ṣe lo àwọn àsìkò tó kù l'áyé rẹ dáadáa!
More