Gbogbo ohun wà ni ìparọ́rọ́: Gbígbà Jésù' Simi ni Kérésìmesì Èyí Àpẹrẹ

All Is Calm: Receiving Jesus' Rest This Christmas

Ọjọ́ 5 nínú 5

Ojó Karùn: Gbẹ́kẹ̀lẹ́ jijẹ́ olóòótọ́ Rè:

“Se o gbẹ́kẹ̀lẹ́ Mi?”

Ìbéèrè yen dojú ko wa lójoojúmọ́, láti ìgbà tí a jí dìde sí ìgbà tí ba fẹ́ lo sùn. Nítorí láti gbékèlé túmò sí láti simi, àtipe láti simi túmò sí láti gbékèlé.

Ronú nípa è: Ó kò ní se ìdákọ̀ró igi kérésìmesì rè ní ìdúró tó ń pàdánù esè kan, àtipe ó kò ní bèrè lówó ènìkan tó n sábà máa ń pẹ́ lẹ́yìn láti mú isé pípé fún ayẹyẹ Kérésìmesì .

Bóyá a mò tàbí a kò mò, nígbà gbogbo lan ronú nípa ipò siṣeé gbẹ́kẹ̀ lé tí àwon ohun àti àwon ènìyàn tó wà láyìíká wa. A se ohun ìkaánnà nínú ìbáṣepò wa pèlú Olórun, a n rọra ń dọ́gbọ́n a nse ìdúnàádúrà bí a máa se gbé ara wa Lé lọ́wọ́.

Bóyá o jé ètò ìnáwó wa ni, ìbáṣepò tó túká, ìpalára tó farasin, tàbí ìsapá ọjọ́ iwájú, a ronú nípa jijẹ́ olóòótọ́ Olórun séyìn láti pinnu bóyá a lè tàbí a kò lè gbékèlé E ní nísinsìnyí wa.

Sùgbón láàárín isé sísé ọlidé èyí ní ìgbékèlé tàbí àìnígbẹ̀ẹ́kẹ̀lé wa túbò hàn gbangba sí.

…A yóò fun ara wa pèlú àwon bisikíìtì, àwon ìpápánu eléròjà, àti hámù olidé tí a kò ba gbẹ́kẹ̀ lé Jésù láti jé Búrẹ́dì Ìyé tó tẹ́ àwon ìfẹ́-ọkàn wa tó jíinè lórùn.

…A yóò dààmú nípa omo wa onínàákúnàátí tí a kò bá gbékèlé Jésù láti jé Olùṣọ́ Àgùntàn tó Dára tó mú àgùntàn tó sonù padà sílé.

…A máa yíràá nínú ìdánìkanwà, nímọ̀lára ìgbàgbé, tí a kò bá gbékèlé Jésù láti jé Ìmánúẹ́lì, Olórun tó n gbé pèlú wa kódà nígbà tí a ba wa ni ìdánìkanwà.

…A gbígbìyànjú láti sèdá Kérésìmesì tó pé, tí a kò bá gbékèlé Jésù láti jé Ènì mímó Olórun tó n se wa ní pípé.

Àsìkò kòòkan jé àǹfààní tuntun láti gbékèlé jijé olóòótọ́ Olórun ni àwon ònà míllíònù kékeré , àtipe gbogbo e bèrè pèlú kíẹ́kọ̀ọ́ láti simi.

Tó bá jẹ́ pé dípò kí a kánjú gìrìgìrì sínú àwon ojó wa tó kún fún isé, a bèrè láràárọ̀ pèlú ìse tó rorun tí ìsimi? È jé kí a, gégé bí onísáàmù se, fún àwon okàn wa ní ìtóni láti wà ìsimi nínú Rè nìkan: láti rántí àwon isé àti dáradára Rè , láti fi ìnílò wa lójú méjèèjì hàn fún U, láti paróró àwon iyè inú wa àti àwon okàn wa níwájú Rè, àtipe láti kéde ìgbọ́kànlé wa nínú jíjé olóòótọ́ Rè.

Nítorí Ènì tó sò ayé sínú ìwalaayé síbè wá gégé bí ìkókó àlaìlólùrànlọ́wọ́ ní mímó, ayọ̀ kíkún, lóru ìdákẹ́jẹ́ẹ́, lè sò ìparóró àti àlàáfíà sínú àwon ayé wa lónìí.

Àwon Ìbéèrè Îjiroro: Èwo nínú àwon orúko Jésù lo sòrò sí o àti àwon ìpèníjà kan pàtó tí o n dojú kó ní ayé rè? Kí ló dà bí láti gbékèlé àtipe simi nínú Olórun ni àkòkò Kérésìmesì yìí? Kí ló ma se ni ònà tó yàtọ̀?

Se ó fé sí ? <. Gbà ẹ̀dà fáìlì Mímú àwọn ewé odò kúrò lórí àwon Orúko Jésù erù àti gbà ìwé ìròyìn àdúrà Àwon Orúko Jésù, àmì ìwé Ìsimi, àti èyí Àdúrà ti à lè tè jáde fún ìsimi Kérésìmesì


Ọjọ́ 4

Nípa Ìpèsè yìí

All Is Calm: Receiving Jesus' Rest This Christmas

Ni àsìkò yìí láti wà ni onímùkẹ́ẹ̀kẹ̀, àmó tún n ṣiṣẹ́ lọ́wọ́ gan. Tẹ̀ lé mi ká lọ fún àkókò díè péré ti ìsimi àti sise ìjosìn tí o máa gbé o ró jákèjádò làálàá àríyá àsìkò náà. Tá gbé karí ìwé Mímú àwọn ewé odò kúrò ní Àwon Orúko Jésù: Bíbò Onífọkànsìn , Ètò kíkà onífọkànsìn ojó márùn-ún yìí yóò ṣamọ̀nà rè láti gbà Jésù’ simi ni Kérésìmesì nípa gbígbà àsìkò láti rántí dáradára Rè, fi áìní rè hàn, máa wá ìdákêjêjê Rè, áti gbékèlé pé olóòótọ́ Ni i.

More

A fé láti dúpé lówó Akéde Moody fún pipèsè ètòbyìí. Fún ìsọfúnni sí i, E jòó ṣèbẹ̀wò: http://onethingalone.com/advent