Gbogbo ohun wà ni ìparọ́rọ́: Gbígbà Jésù' Simi ni Kérésìmesì Èyí Àpẹrẹ
Ojó Kíní: Ìdí tí a fi Nílò Ìsimi ní Kérésìmesì
“Se àwon Gbọ̀ngàn lọ́ṣọ̀ọ́ pélú ẹ̀ka-igi holly,” Carol tí a mọ̀ ọ́ dáradára bèrè. Àti awa náà.
Àwọn kan lára wa múra sílè fún Kérésìmesì ní àkíyèsí èkíní òtútù tójú ọjọ́, nígbà tí àwon mìíràn sún ohun ti kò se kò sílè síwájú bi gun bi o ti ṣee.
Àmó ìgbà kan gbogbo wa wó nú ìyíbírí isé sisé—òpò è ti fàájì àti àjọyọ̀ sùgbón rè éni tenutenu bí ó ti wù kí ó rí, o n fi àwon okàn wa ní nímólarà méjèèjì sù ú àti òfifo. Lópò ìgbà, o wà ní àárín ariwo yànmù ọlidé oyàyà yìí ni a máa rora ṣe kàyéfì, “se gbogbo ohun tó wà níbe leyi?” Ìròhìn Ayọ̀ ní Yàtọ̀ sí inú àwo pẹrẹsẹ bisikíìtì, àkọsílẹ̀ ọjà rírà, àti ìselóge ní Omo Olórun se ni ènìyàn fún wa.
Olórun mò pé a ní ìtẹ̀sí ìdìhámọ́ra oníjàgídíjàgan isé sisé. Èyí jé oókan lara ìdí tí O fi kó ojó ìsimi fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní gbogbo ojó mẹ́fà mẹ́fà—pé kí wón lè mú ise wón dúró àtipe mò daju dáradára tí Olórun wón, ìnílò wón fún U n lójú méjèèjì, àti èbùn Rè ti ìparọ́rọ́.
Ní sise àṣà ìsimi, a jẹ́wọ́ ipo ìgbẹ́kẹ̀ lé Olórun: kódà nígbà tí a dáwọ́ isé dúró, Olórun máa bá lọ láti mú ayé wa pa pò.
Lọ́dún yìí mo pèwá, gégé bí Olúwa àti Olùgbàlà wa se pè àwon ọmọ ẹ̀yìn Rè, láti wá sínú pèlú Rè àti gba ìsimi, láti tẹ̀ ẹ́ jẹ́jẹ́ àti síṣàtúnrí àgbàyanu àti ìdùnnú tí àsìkò Kérésìmesì ní àárín ọlidé tó o fẹ́ràn jù nínú àṣà àtọwọ́dọ́wọ́.
Sùgbón kí ni èyí dà bíi?
Lórí àwọn ọjó mérin tó n bo, a máa se àṣà ìjọsìn ìsinmi lilo ìkékúrú orúkọ ÌSIMI: rántí dáradára Rè, fi ìnílò rè hàn, wá ìparọ́rọ́ Rè, àti gbẹ́kẹ̀ lé olóòótọ́ Rè.
Se wàá gbà Ìkésín Rè ní àsìkò Kérésìmesì yìí? Wá fúngbà díè, kí o simi.
Àdúrà: Oh Olúwa, E mò mi dáadáa. E mò pé mo fé àkókò àgbàyanu pèlú ebí àti ará, àmó mo sàṣejù, se àpòju, àti ṣíṣàṣerégèé, àtipe ni ìparí, òpò àìfararo àti ìpalára wà tó n lo káàkiri. Mí kò fé yen lọ́dún yìí. Nítorí náà mo wàá sódò Yín pèlú apá ṣí sílẹ̀ àti okàn ṣí sílẹ̀. Níhìn-ín ní mo wá. E kó mi láti ṣe àjọyọ̀ ìbí Olùgbàlà wa láti ibi ìsimi. E yí okàn mi láti níbàgbàyanu Ewà Yín àti korin ìyìn Yín. Àmín.
Se o fé sí? Gbà ẹ̀dà fáìlì mímú àwọn ewé odò kúrò lórí àwon Orúko Jésù erù àti gbà ìwé ìròyìn àdúrà Àwon Orúko Jésù, àmì ìwé Ìsimi, àti èyí Àdúrà ti à lè tè jáde fún ìsimi Kérésìmesì.
Nípa Ìpèsè yìí
Ni àsìkò yìí láti wà ni onímùkẹ́ẹ̀kẹ̀, àmó tún n ṣiṣẹ́ lọ́wọ́ gan. Tẹ̀ lé mi ká lọ fún àkókò díè péré ti ìsimi àti sise ìjosìn tí o máa gbé o ró jákèjádò làálàá àríyá àsìkò náà. Tá gbé karí ìwé Mímú àwọn ewé odò kúrò ní Àwon Orúko Jésù: Bíbò Onífọkànsìn , Ètò kíkà onífọkànsìn ojó márùn-ún yìí yóò ṣamọ̀nà rè láti gbà Jésù’ simi ni Kérésìmesì nípa gbígbà àsìkò láti rántí dáradára Rè, fi áìní rè hàn, máa wá ìdákêjêjê Rè, áti gbékèlé pé olóòótọ́ Ni i.
More