Gbogbo ohun wà ni ìparọ́rọ́: Gbígbà Jésù' Simi ni Kérésìmesì Èyí Àpẹrẹ

All Is Calm: Receiving Jesus' Rest This Christmas

Ọjọ́ 4 nínú 5

Ojó Kerin: Wá ìparọ́rọ́ Rè

Se o tí nímọ̀lára tí Èmí Mímó tó ń sún e láti ní ìsimi lọwọ àwon ìmúra sílẹ̀ olidé àti jòkòó fúngbà díè níwáju Jésù’, láti pa a tì nìkan àti darí àfiyèsí rẹ sórí iṣẹ́ tó tẹ̀ lé e lórí àtòko rè?

Mo mò pé Mo tí se.

A sábà ń máa gbìyànjú ara wa láìjáfara rárá ńṣe ìyárasáré, jíjí ní kùtùkùtù òwúrọ̀ àti máa ṣàìsùn dòru, fífún gbogbo wákàtí ò̩sán fún gbogbo ìyí rè. Nígbà náà a sàárẹ̀ nípa kòókòó jàn-ánjàn-án wa, a kì í sábà gbádùn ewà àkókò náà.

Àtipe nígbà mìíràn, isé síse yìí jé ní tòótọ́ ìdíbọ́n láti pa ìpalára tó jinlè mó. Tí o ba jé pé a ń ṣiṣẹ́ lọ́wọ́, a kò ní láti gbà pé àwon ogbé sísọ tó ń sọni di akúrẹtẹ̀ tí a gbé. A bèrù ìparọ́rọ́, nítorí náà a kò fi isé kánkán sílè láìse, bó tilè jé pé a kobi ara sí ìwà ìkà kánjúkánjú tó n halè mó wa to dáwọ́ aago pa dà sẹ́yìn tún wa.

Síbè ìdáhùn kì i se tìtì àwon àsà wa sóde ojú fèrèsé àti di ènìyàn búburú. Kàkà bẹ́ẹ̀, a gbódò mú àsìkò ìparóró wonú isé sísé kí a bá lè sísé láti ibi àpapọ̀ àti ìsimi. Òtítọ́ ní pé ìgbàlà Olórun wà sí wa nígbà tí a ba ronú pìwà dà àti simi, agbára Rè nígbà tí a wà ní ìdákëjë àti gbékè lé.

Àkókò Kérésìmesì yìí, láyà láti paróró, kódà tó bá jé fún ìṣẹ́jú méjì lójoojúmọ́. Mú àkọsílẹ̀ rè to Olúwa àti to sí ìtìsẹ̀ Rè. Gbádùn ewá ìwájú Rè bí ó se ronú lórí àwon orúko Rè àtipe fún láàyè láti wò ìpalára tó jinlè sàn.

Sò ipò Olúwa Rè sórí ayé rè; fi ìnílò rè fún U hàn lójú méjèèjì, àtipe fún láàyè ara rè láti dúró niparọ́rọ́. Máa yọ̀ níwáju Rè.

Òun ní Ìmánúẹ́lì—Olórun pèlú wa. Ó ríran. Ó mò. Ó gbó. Jé kí Ó pètù è pèlú ifé Rè.

Àdúrà: Pètù sokàn mi pèlú ifé Yín, Olúwa. È sò àlàáfíà Yín sórí ayé mi gégé bí È tí sòrò ìparọ́rọ́ sórí òkun onípákáǹleke. Mú ìwòsàn àti ìmúpadàbọ̀sípò sí ìrora inú okàn mi látowo ìpadanu a ènì tí mo féran, faradà ìṣẹ̀lẹ̀ tí ń bani nínú jẹ́ tàbí hílàhílo tí okàn, láti ìrètí tó já sófo àti ìlépa tó parun. Èyín, Àjíǹde àti Ìyè, E mí èémí ayé tuntun sínú àwon èyá ara tó dokú ní okàn mi. Tanná ran ìrètí tuntun nínú mi fún ojọ́ iwájú. È kó mi láti síbè àti gbà afúnniníyè ìwájú Yín. Àmín.

Ọjọ́ 3Ọjọ́ 5

Nípa Ìpèsè yìí

All Is Calm: Receiving Jesus' Rest This Christmas

Ni àsìkò yìí láti wà ni onímùkẹ́ẹ̀kẹ̀, àmó tún n ṣiṣẹ́ lọ́wọ́ gan. Tẹ̀ lé mi ká lọ fún àkókò díè péré ti ìsimi àti sise ìjosìn tí o máa gbé o ró jákèjádò làálàá àríyá àsìkò náà. Tá gbé karí ìwé Mímú àwọn ewé odò kúrò ní Àwon Orúko Jésù: Bíbò Onífọkànsìn , Ètò kíkà onífọkànsìn ojó márùn-ún yìí yóò ṣamọ̀nà rè láti gbà Jésù’ simi ni Kérésìmesì nípa gbígbà àsìkò láti rántí dáradára Rè, fi áìní rè hàn, máa wá ìdákêjêjê Rè, áti gbékèlé pé olóòótọ́ Ni i.

More

A fé láti dúpé lówó Akéde Moody fún pipèsè ètòbyìí. Fún ìsọfúnni sí i, E jòó ṣèbẹ̀wò: http://onethingalone.com/advent