Gbogbo ohun wà ni ìparọ́rọ́: Gbígbà Jésù' Simi ni Kérésìmesì Èyí Àpẹrẹ

All Is Calm: Receiving Jesus' Rest This Christmas

Ọjọ́ 3 nínú 5

Ojó Keta: Fi ìnílò rè hàn:

“E seun, àmó mo lè se.”

Ñjé o ti kò láti gbà ìpésé fún ìrànlọ́wọ́ ri, bó tilè jé pé o nílò rè gan?

Nígbà mìíràn o ní láti gbà pé a kò lè se gbogbo ohun nípa tìkára wa. Láàárín gbogbo ìmúrasiílè wa fún Kérésìmesì, èyí nígbà mìíran yorí sí àárè àti rirẹ̀ tẹnutẹnu. Sùgbón moní-tómi tìkára ènì èyí kaánnà lè di aṣekúpani nínú ìgbé ayé èmí wa.

Òtító Ni pé à nílò Jésù. Sùgbón lópò ìgbà Ni a gbé ìgbé ayé wa bé ni pé a lè mú kí nǹkan máa ṣẹnuure lórí ara wa. Títí dìgbà tí a lo àkókò láti ronú lórí ewà Olórun—Ìjémímó Rè, ifé Rè áti inú rere Rè, ìrúbo ètùtù Rè—pé a mò lẹkun-un-rẹrẹ bí a se nílò Rè lójú méjèèjì. Ìjàǹbá n bẹ́ẹ̀ pèlú jijéwó àìní wa, àmó Jésù selérí pé àwon tó n se aláìní nínú èmí, tó n jé olókàn tútù, àtipe tó n pòùngbẹ fún ìjémímó, a san èrè pèlú òpò Olórun fúnra Rè sí i.

Ó ṣẹlẹ̀ pé fifi ìnílò wa hàn jé ònà Kan soso láti gbà àwon ọrọ̀ ológo ti Kristi Jésù tí Olórun tí sètò sílè fún wa.

Onísáàmù ké pè àwon èèyàn Olórun láti se ìjosìn, forí balè, àti kúnlè níwájú Olùṣẹ̀dá wón. Èdè hébérù fún ìjosìn túmò sí láti dọ̀bálẹ̀ tàbí forí balè. Ni tara, èyí túmò sí láti terí àwon orúnkún wa ba ni ìmọrírì ipò Olúwa Jésù’; Ni tèmí, ó túmò sí láti juwó sílè gbogbo tí a jé si gbogbo tí Ó jé.

Irú títo lètò ti ojú ìwòye àti àwon ohun pàtàkì jù lọ èyí ṣeé ṣe nígbà tí a ba kókó lo àkókkò ni mimò títóbi Olórun; ìjosìn sún wa si ìwòye tó dára ti Olórun, tó sún wa si ìjẹ́wọ́ àti ìronúpìwàdà.

Jésù sọ àpèjúwe kókó pàtàkì nígbà tí Ó pè ara Rè ni Àjàrà, àti àwon ọmọ ẹ̀yìn Rè jé èka. “Láìsí Èmi, è kò lè se ohunkóhin,” Ó so fún wón. “Àmó tí e bá dúró nínú mi […] è yóò so èso púpò.” Lọ́nà tó yanilẹ́nu, Jésù kò pè wa láti ṣe làálàá láti so èso púpò; kàkà bẹ́ẹ̀, O pè wa láti gbé nínú Rè, láti dúró de E. Àwon tó dúrò wa ni ìsopò sí I máa so èso púpò lónà àdánidá, nítorí Èmí Rè ní Ènì tó n pèsè èso náà.

Jé kí ìnílò rè fún Jésù mú o si ìsimi àti ìparóró ní Kérésìmesì yìí. Pákáǹleke kúrò. Ó kò ní láti ṣe gbogbo e fúnra rè nìkan. Kódà, o kan ní láti simi.

Àwon ìbéèrè Ìjiroro: Báwo ní àwòrán Jésù gégé bí Àjàrà se nípa lórí è? Àwon orúko Jésù wo ni o gbé e láti mò ìnílò rè fún U? Ònà kan wo ni o lè gbà láti fi ìnílò è hàn àti simi nínú Rè lónìí?

Ọjọ́ 2Ọjọ́ 4

Nípa Ìpèsè yìí

All Is Calm: Receiving Jesus' Rest This Christmas

Ni àsìkò yìí láti wà ni onímùkẹ́ẹ̀kẹ̀, àmó tún n ṣiṣẹ́ lọ́wọ́ gan. Tẹ̀ lé mi ká lọ fún àkókò díè péré ti ìsimi àti sise ìjosìn tí o máa gbé o ró jákèjádò làálàá àríyá àsìkò náà. Tá gbé karí ìwé Mímú àwọn ewé odò kúrò ní Àwon Orúko Jésù: Bíbò Onífọkànsìn , Ètò kíkà onífọkànsìn ojó márùn-ún yìí yóò ṣamọ̀nà rè láti gbà Jésù’ simi ni Kérésìmesì nípa gbígbà àsìkò láti rántí dáradára Rè, fi áìní rè hàn, máa wá ìdákêjêjê Rè, áti gbékèlé pé olóòótọ́ Ni i.

More

A fé láti dúpé lówó Akéde Moody fún pipèsè ètòbyìí. Fún ìsọfúnni sí i, E jòó ṣèbẹ̀wò: http://onethingalone.com/advent