Idalare Nipa IgbagboÀpẹrẹ

Idalare Nipa Igbagbo

Ọjọ́ 7 nínú 7

Irugbin Ileri

Nígbàtí Ọlọrun ṣe ileri Rẹ fún Abrahamu Òun wò tayọ Isaki. Ọlọrun n wò imuṣẹ ọrọ ti O sọ nínú Ọgbà Edẹ̀ni nipa "Èsó Ọmọ Obirin"

Dájúdájú, Ọlọrun ni wò kọjá àkókò Òfin àti igbã Abrahamu. Òún wò imuṣẹ ọrọ Rẹ nipa Ìràpadà ẹdá ènìyàn ati mímu ìgbàlà wá sí ayé láti ọdọ Kristi to jẹ "Èsó Nà".

Báwo ni eleyii ṣe kan ọ? Èyí pe fún akitiyan to péye ní ọdọ rẹ láti fi Jésù Kristi ṣe afojusun ìgbàgbọ, Ohun nikan láì sí òhun míràn tàbí ẹlomiran.

Jésù ni ileri ti Ọlọrun pèsè fún ìgbàlà rẹ. Ohun ni Èsó Òdòdó eniti a tí mú Òdòdó wá fún gbogbo ẹdá ènìyàn. Ko sí onà miiran to lati fi èrè fún ìgbàgbọ́ rẹ ju wípé kí o fi mulẹ bi idákọró nínú Kristi Jésù.

Siwaju kika: Genesisi 3:15, Heberu 12:2, Roman 5: 17-19, Ifihan 13:8.

Adura: Jésù Olùwà, jẹki ìgbàgbọ́ mi dúró láì yẹ nínú Rẹ nikan.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 6

Nípa Ìpèsè yìí

Idalare Nipa Igbagbo

Gbogbo eniyan ni afi fún lati de ipò ìdáláre, tá owá ni àlàáfíà pẹlu Ọlọrun ati ará wa, nínú ìmọ pé Ọlọrun ti dariji ọ ati pé otí pa gbogbo ifisun rẹ àti ìdálẹbi rẹ rẹ́, kó ni óhùn kán sí ọ ṣugbọn O ri ọ gẹgẹbi òdodo Rẹ, O fẹràn rẹ, òsì ni ọpọlọpọ ileri ti O fi pámọ́ fún ọ. Ìgbé ayé ìyanu ni eyi jẹ! Ṣugbọn kini a nilo lati lè gbé igbeaye yii tabi ṣe oṣe ṣe?

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL