Idalare Nipa IgbagboÀpẹrẹ

Idalare Nipa Igbagbo

Ọjọ́ 5 nínú 7

Eegun Ofin

Yíò jẹ ìgbé ayé ikuna kúrò ninú ìgbàgbọ́ bi o bá de àrà rẹ mọ òfin ẹsìn gẹgẹbi bi ohun tí a béèrè fún ìgbàlà rẹ àti lati gbé nínú Kristi. Eleyii yíò jẹ idiwọn lori ìgbàgbọ rẹ, yóò fi iṣẹ àrà di ayé ore ọfẹ bi ohun tí a ofi ni ìgbàlà.

Awọn to dojukọ Paulu julọ nínú ìlépa imuṣẹ ihinrere ni awọn ẹlẹsin Jù, kinidi? Wọn lero pé Paulu ṣe irira si òfin ati sí tẹmpili, wọn fi ẹsùn kàn na kàn Jésù.

Wọn fọ́jú tó bẹẹ ti wọn ko ri ìpèsè ìgbàlà ati ìràpadà Ọlọrun ti n'bẹ níwájú wọn débi tí wọn o gbãgbọ.

Ẹkọ nlá to wá nibiyii rè; bo tilẹ wú kí awọn Ilana ati ofin ìjọ rẹ ti dára tó, àkò gbọdọ ṣe wọn ni ará ohun tí a béèrè fún ìgbàlà tabi ìdáláre rẹ nínú Kristi " Nipa Ore ọfẹ l'afi gbawa là nínú ìgbàgbọ, olódodo yíò wá nipa igbagbọ.

Siwaju kika: John 1:11, Roman 1:17, Efesu 2:5-9, Iṣe 14:1-7, 19-20,15:1-5,17:1-6

Adura: Mo gbà ominira Kúrò labẹ ide ẹ́gún ofin ẹsin.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 4Ọjọ́ 6

Nípa Ìpèsè yìí

Idalare Nipa Igbagbo

Gbogbo eniyan ni afi fún lati de ipò ìdáláre, tá owá ni àlàáfíà pẹlu Ọlọrun ati ará wa, nínú ìmọ pé Ọlọrun ti dariji ọ ati pé otí pa gbogbo ifisun rẹ àti ìdálẹbi rẹ rẹ́, kó ni óhùn kán sí ọ ṣugbọn O ri ọ gẹgẹbi òdodo Rẹ, O fẹràn rẹ, òsì ni ọpọlọpọ ileri ti O fi pámọ́ fún ọ. Ìgbé ayé ìyanu ni eyi jẹ! Ṣugbọn kini a nilo lati lè gbé igbeaye yii tabi ṣe oṣe ṣe?

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL