Idalare Nipa IgbagboÀpẹrẹ

Idalare Nipa Igbagbo

Ọjọ́ 1 nínú 7

Kii ṣe Nipa Awọn Ofin Ẹsin

Ọkàn nínú ohun to ṣe pàtàkì ìrírí fún ẹni gbá Jesu ni gbígbà Ẹmi Mimọ, Ẹni tó wa láti mú iṣẹ Kristi ṣẹ nínú wa.

Nipa bẹ, aya ìgbà yí sọtọ sí àkókó Ofin Majẹmu Lailai. Áwa gbà ẹmi isọdọmọ akii ṣe ẹrù sí pipa ofin mọ.

Pàtàkì níní ẹmí mímọ kó ni ni ìtumọ tàbí igbero ti àbá tun pada sínú òfin ẹsìn lati di olódodo.

Nibiyii Paulu bá awọn ijọ Galatia wí, pe wọn gbé òhún ti wọn ti Gba ti nínú èro lati tún gbà nipa pipa ofin ikọla ati agbekalẹ awọn Jù.

Ìgbàlà rẹ nínú èyí ti ìràpadà ati ìdáláre rẹ wa, afi fún ọ nípa Ore ọfẹ òsì gbà nipa igbagbọ ni. Nipa bẹ iwọ di òdodo Ọlọrun nipa igbagbọ nínú Kristi kii ṣe nipa titele òfin ẹsìn.

Kòsí ẹni to tọ Kristi wà gẹgẹbi ẹni tí àti wẹ mọ, tí àti dálarè, to ti di olódodo ki ato gbàá là ati lẹyìn ìgbàlà àkò ni ọnà miran fún iwẹnumọ yatọ sí ìrúbọ Kristi ti Ẹmi Mimọ ṣe làṣẹ pe.

Siwaju kika: Roman 8:14-16, Heberu 9:13-14,

Adura: OLUWA jẹ́kin ri Ọ àti iwọ nikanṣoṣo gẹgẹbi orísun iwẹnumọ ati ìdáláre mi

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 2

Nípa Ìpèsè yìí

Idalare Nipa Igbagbo

Gbogbo eniyan ni afi fún lati de ipò ìdáláre, tá owá ni àlàáfíà pẹlu Ọlọrun ati ará wa, nínú ìmọ pé Ọlọrun ti dariji ọ ati pé otí pa gbogbo ifisun rẹ àti ìdálẹbi rẹ rẹ́, kó ni óhùn kán sí ọ ṣugbọn O ri ọ gẹgẹbi òdodo Rẹ, O fẹràn rẹ, òsì ni ọpọlọpọ ileri ti O fi pámọ́ fún ọ. Ìgbé ayé ìyanu ni eyi jẹ! Ṣugbọn kini a nilo lati lè gbé igbeaye yii tabi ṣe oṣe ṣe?

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL