Idalare Nipa IgbagboÀpẹrẹ
Pipe nipa Ẹmí Mimọ
Ìgbé Àyè Kristeni jẹ igbe-aye ti ẹmi to hàn nípa tara kii ṣe ìgbé ayé èsìn bibẹkọ aṣiṣe igbekalẹ awọn òfin lati dẹni to pé yíò gbilẹ.
Nígbà to bá sí ri bayii awọn ìwà inọkasini, ìdálẹbi, jíjẹ mimọ jùlọ ati ṣiṣe ìdájọ yíò gbilẹ nàá, eleyii lè tù ipejọpọ Kristẹni kà yíò mú kí agabagebe ma bisii.
Wàá ni ìwà ìrẹlẹ ọkan ati òré ọfẹ sí ẹlomiran nigbati o bá mọ wípé idagbasoke rẹ nipasẹ iranlọwọ Ẹmi Mimọ ni, Kiiṣe ṣiṣe rẹ tabi titẹle ofin ati ilana ẹsin.
Ibaṣepọ rẹ pẹlú Ẹmi Mimọ ni yíò ran Ọ lọwọ láti tẹri ẹran àrà bá tí yó sí fún ọ ní iṣẹgun lórí ẹṣẹ Kiiṣe titẹle ati pipa Òfin ẹsìn mọ.
Siwaju kika: Gal.6:1-2, Gal.5:16-18.
Adura: Ẹmi Mimọ, ran mi lọwọ láti mọ ayē Rẹ nínú ayé mi lati lè bá Ọ rin.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Gbogbo eniyan ni afi fún lati de ipò ìdáláre, tá owá ni àlàáfíà pẹlu Ọlọrun ati ará wa, nínú ìmọ pé Ọlọrun ti dariji ọ ati pé otí pa gbogbo ifisun rẹ àti ìdálẹbi rẹ rẹ́, kó ni óhùn kán sí ọ ṣugbọn O ri ọ gẹgẹbi òdodo Rẹ, O fẹràn rẹ, òsì ni ọpọlọpọ ileri ti O fi pámọ́ fún ọ. Ìgbé ayé ìyanu ni eyi jẹ! Ṣugbọn kini a nilo lati lè gbé igbeaye yii tabi ṣe oṣe ṣe?
More
A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL