Dídaríji àwọn tó páwa láraÀpẹrẹ
Ìpìlẹ̀ Ìdaríjí
Kí lo máa se tí o bá rí àléébù àwọn ẹlòmíràn?
Òpò lára wa lọ ń gbé ogbe èmi káàkiri tí a fi palára látọwọ́ àwọn mìíràn. Àwọn tó páwa lára lè kan tí sọ pé “Má bínú” wón sí bá tiwọn lọ. Bóyá wón sé béè ni pé kòsí ohun ìpalára kánkan tó ti ṣèle. Se o sòrọ fún é láti gbàgbé àwọn ohun tó ṣẹlẹ̀ gángan? Se o ń yẹra fún àwọn tó pá o lára? Ní ìdá kejì, bóyá àwọn mìíràn tí yera fún e nítorí àwọn ohun àìdá tí ìwo tí se.
Ní àkàwé yìí Jésù pé ìránṣẹ́ náà ní búburú nítorí, léyìn tó rí ìdaríjí gbà, kò ṣe bákan náà sí ẹlòmíràn. Kàkà bẹ́ẹ̀, o fi àwọn onígbèsè rè sórí ọ̀pá ìdiwọ̀n to ga jù bí òun ṣe fi ará rè. Bí a tín kà àyọkà yìí ọkàn wa ké síta, “Èyí ko dáa!” A lè rí àìṣèdájọ́ òdodo tó hàn kédere: o yé kí ìránṣẹ́ yìí dáríjì àwọn tó jẹ ẹ́ lówó.
A mo àti fé àìséojúsàájú mò nítorí òòrè ọfẹ Olórun tó wópò sí wa. Báwo ló ṣe yẹ kí a dáhùn padà sí àwọn àṣìṣe àwọn mìíràn? Àyọkà yìí kì wa nílọ nípa fífi áìnídaríjí sínú ọkàn wa. Níhìn a rí i gégé bí Ọlórun se rèti pé kí a dáhùn sí àwọn ìwà esè àwọn mìíràn—O rèri pé kí a dáríjì. Lórí ìdiwọ̀n wo ní Olórun rèti èyí? A gbé irètí èyí lórí ìdaríjí onife ti O ní sí wa. A sábà máa ń often ṣèdájó àwọn mìíràn pèlú ìdiwón tó yàtò sí èyí ti a fin sèdájó ará wa.
A rí èsè àwọn mìíràn tí wón hù ṣì wà gégé bí ohun tó burú gan jù àwọn àṣìṣe wa, tàbí a ń reti pé kí wọn fi àànu nlá hàn jù bí a wa tí ṣetán láti gbà láàyè. Olórun kò fi ààyè gbà irú ìwà yìí fún wa. Kàkà bẹ́ẹ̀, O fé kí a rántí àànú Rè kí a sí ṣe bi Òun. Nígbẹ̀yìngbẹ́yín, àwọn àṣìṣe wa sí àwọn mìíràn jé àṣìṣe sí Ọlọ́run. O ṣèdá oòkan kan wà O sí fé kí a rí ará wa gégé àwọn tó seyebíye, kódà fifi àìní wà nípò kejì sí tí àwọn mìíràn (Fíllípì 2:1-4). O hàn kédere pé O tí gbé ìdiwón ìdaríjí to gá— ìyẹn ẹbùn ìgbàlà wa.
Báwo ló ṣe lè yípadà? Se àkọsílẹ̀ àwọn ònà tí Ọlọrun tí dáríjì o. Ságbéyẹ̀wò ìfẹ Ọlórun tó ga fún: nínú Kristi O pèsè ònà fún láti gbà ìdariji, kódà bilí o ṣe kọ Ọ sílè (Róòmù 5:8). Bèrè sí ní to náwo ìdaríjí sí àwọn mìíràn, kìí ṣe lórí ìmólárá, àmó lórí ìpìlè èbùn òòrè ọfẹ àti àànu Olórun tí fi fún e.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Bóyá a nje ìrora ojú ogbé okàn tàbí tí ara, ìdaríji ní ìpìlê ìgbé ayé Kristẹni. Jésù Kristi nírírí onírúurú ohun tí kò tọ̀nà àti hùwàsí ti kódà títí dé ikú àìtó. Síbè ní wákàtí tó kéyìn, o daríji olè tó ṣe yèyé é lórí àgbélèbú àti bákan náà àwọn múdàájọ́ṣẹ e.
More