Dídaríji àwọn tó páwa láraÀpẹrẹ
Èbùn Ìdáríjini
Òpòlopò wa ñbá ara wa jà tí kò sí ní ìyanjú, àìbáraení sòrò pèlú ìkùnsínú lãrín àwa àti àwon elòmíràn. Sùgbón ìrètí nlá wà fún wa! Olórun tí se àpere ìjo láti jé ìpéjopò onígbàgbó tí wón ñgbé ní àlàfíà pèlú ara wón. Nínú àkosílè yí, a tí kò àwon onígbàgbó "láti jé alaanu.... onínúrere tí ó ñdáríjini. Àse láti jé alaanu àti onínúrere tún jé àfikún àse láti dáríjini. Ìdáríjini jé èbùn tí à ñfún àwon míràn; ìgbé aiyé ìfi araeni rúbo nínú èyí tí a tú wón sílè kúrò nínú èsè tí wón sé wa. Níwòn ìgbàtí Olórun tí jòwó omobíbí Rè láti bo èsè wa mólè, ó seé sé fún wa láti dáríji àwon elòmíràn. Olórun tí san gbèsè èsè wa. A tí fí ònà lele fún wa láti kópa nínú èbùn ïrúbo Olórun nínú Kristi nígbàtí a bá dáríji àwon míràn
Ìwúnilórí fún ïtèsíwájú ìfé báyi ní a kò rí nínú okàn wa. Kàkà béè, ìwúrí yí wa láti òdò Olórun àti gbogbo ohun tí ó sé láti dáríji wa nínú Kristi. A níláti san gbèsè nítorípé a tí se àwon àsìse tí ó po gidi. Bí ó tí wu kí ó rí, nígbàtí a bá jòwó àsìse tí àwon elòmíràn sé sí wa lówó, àwa náà ní ìgbekèlé nínú õre-òfé Olórun láti san gbèsè tiwa. Eléyi jé ìtúsílè tí ó péye nínú ìgbé aiyé wa. Ó kà wa ye láti jé ìgbádùn òmìnírá nínú Kristi àti ìbásepò tí ó lárinrin pèlú àwon elòmíràn. Bí a bá fí ojú inú wo òmìnírá àti ìfé inúrere tí a ó rí gégébí ìrírí wa nípa ìbásepò wa àti ìdáríjini tí ó kún láìsí àbàwón. Ìbásepò wa gégébí onígbàgbó ní a mú dúró sinsin tí a sí fún l'agbára nípa aanu, inúrere àti ìbásepò tí ó kún fun ìdáríjini.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Bóyá a nje ìrora ojú ogbé okàn tàbí tí ara, ìdaríji ní ìpìlê ìgbé ayé Kristẹni. Jésù Kristi nírírí onírúurú ohun tí kò tọ̀nà àti hùwàsí ti kódà títí dé ikú àìtó. Síbè ní wákàtí tó kéyìn, o daríji olè tó ṣe yèyé é lórí àgbélèbú àti bákan náà àwọn múdàájọ́ṣẹ e.
More