Àgbàrá Ìyìn Tó Ṣàrà Ọ̀tọ̀: Ètò Ìfọkànsín Olóòjọ́ Márùn-ún Láti Inú Ìwé Orin DáfídìÀpẹrẹ

The Extraordinary Power of Praise: A 5 Day Devotional From the Psalms

Ọjọ́ 2 nínú 5

Yíyìn Ọlọ́run Ma Fúnwa Lókun Bí A Ṣe Ń Retí

Onísáàmù Dáfídì ní láti mú sùúrù fún ìgbà pípẹ́ ki Olórun tó mú ìlérí pé o máa di ọba wá sí ìmúṣẹ. Lọ́pọ̀ ìgbà ní àkókò tó dúró dé ìlérí náà, Dáfídì tún sá pamọ́ fún ẹ̀mí rẹ̀ bí Ọba Sọ́ọ̀lù ti ń lépa láti ṣekú pa á. Dípò kí o kúrò nínú ìgbàgbọ́ rè nínú Olórun, Dáfídì tẹ síwájú sí í kódà nígbà tí o ń retí. Nígbà kan láàrín àsìkò tó ń rèti, Dáfídì fi iyìn rẹ hàn nípa siso pè, “Ní òwúrò Mo gbé àwọn ìbéèrè Mi ká ìwájú Rè mọ sí dúró nírètí” (Orin Dáfídì 5:3). Gbólóhùn yìí “dúró nírètí” sòrò nípa ìrètí onígboyà. Kìí ṣe pé Dáfídì kìí ṣe ojúlówó. Ní ìbèrè, Nínú Orin Dáfídì ori 5, o.mi kanlè fún Olúwa láti fetísílẹ̀ kí O sí gbó ìdárò e (Orin Dáfídì 5:1). Àmó, léyìn tí o sọ edùn ọkàn rè pọkàn pọ̀ sí yìnyín Ọlọ́run pè Ọ máa dáhùn. Bí o ń se yín In, Èmí Mímó fún ọkàn é ni òkun pèlú ìrètí onígboyà. Èyí ni àgbàrá ìyìn tó sàrà òtò.

Bí o ń se dúró kí Ọlórun gbó ádùrá e, máa ń tẹ̀ lé àpẹẹrẹ. O so òùngbẹ ọkàn é sí Olórun òdodo aláìlábòsí, àmó pọkàn pọ̀ si yìnyín Olórun. Ọ máa dáhùn nítorí Ọ ṣèlérí pé Òun máa gbó ádùrá e. Ìgbà gbogbo ni Ọ máa mú àwọn ìlérí se gégé bí Ọlọ́run mímó. Bí o ń tésíwájú láti máa yìn Olórun kódà nígbà tí o bá dá bí pé Kò fóhùn, Èmí Mímọ̀ máa fún ọkàn é lókun pèlú ìrètí onígboyà.

Selah – Pause and Reflect: Ìpèlè wo ní nínu ayé lọ ń retí o in your life are you waiting for breakthrough? Báwo ní yìnyín Olórun fún might praising God for His character, fún ìrètí lókun bí ọ ń se rèti?

Ádùrá Ìyìn: Olúwa Ọlórun Mo yín O pé È dára È sí jé Mímó. É yin ní Olórun tó ń mú ọrọ Yìn se nígbà gbogbo. É ṣeun pé É ṣèlérí pé tí mo bá bèrè, É máa dá mi lóhùn hùn (Mátíù 7:7). Mo yìn Yin pé É gbó ohùn mi nígbà gbogbo àti pé Mo lè gbẹ́kẹ̀lẹ́ Yìn láti mú àwọn ìlérí Yín sé (Orin Dáfídì 5: 3, 2 Kọ́ríńtì 1:20). É ṣeun pé bí mo ń se yin Yín lónìí, É kún ọkàn mi pèlú ìrètí onígboyà.

Orin Dáfídì 5:3, “Ni òwúrò, Olúwa È máa gbó ohùn mi; ilni òwúrò ni Mo gbè àwọn ebè ádùrá ìbéèrè ká iwájú Rè tí mo ṣì dúró ní ìrètí.”

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 1Ọjọ́ 3

Nípa Ìpèsè yìí

The Extraordinary Power of Praise: A 5 Day Devotional From the Psalms

Àníyàn, ìfọ̀yà, ìdánìkanwà àti ìsoríkó tí dìde gidi gàn láàárín ọdún mélòó kan tó kọjá. Àwọn èrò ìmólárá wonyìí kìí ṣe tuntun si àwọn Onísáàmù. Àmó, wón kó láti tú àgbàrá ìyìn tó ṣàrà ọ̀tọ̀ jáde láti bórí. Ṣàwárí àṣírí láti fọkàn rẹ̀ balẹ̀ nínú àwọn ìfọkànsin yìí láti ìwé Orin Dáfídì.

More

A fé dúpẹ lówó ilé ìṣẹ́ Moody Publishers fún ìpèsè ètò yí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ́ lọ sí: https://www.moodypublishers.com/the-extraordinary-power-of-praise/