Àgbàrá Ìyìn Tó Ṣàrà Ọ̀tọ̀: Ètò Ìfọkànsín Olóòjọ́ Márùn-ún Láti Inú Ìwé Orin DáfídìÀpẹrẹ

The Extraordinary Power of Praise: A 5 Day Devotional From the Psalms

Ọjọ́ 4 nínú 5

Yíyin Ọlọ́run Máa Mú Ìtẹ́lọ́rùn Wá

Ó jẹ nkán tí ó rọrun fúnwa lóde òní nínú àṣà wa láti máa kerora àti saroye lórí ohùn tí a kòní. A máa nṣe àkàwé ipò tí a wa pẹlu tí àwọn ẹlẹgb ẹ wa, a sì máa nṣe bí wípé wọn sàn jù wa lọ. Nínú àìní itẹlọrun wa, a o sí máa kún àti kerora. Dafidi ṣe àkọsílẹ̀ pe nítorí Olúwa ní olùṣọ àgùntàn oun, òun kòsí náà ni ohùn kàn (Orin Dafidi 23:1). Nínú Orin Dafidi míràn, o kọ wípé Ọlọrun nìkàn ní ìmọ òun àti ago oun.(Orin Dafidi 16:5)

Kílò mú Dafidi wà síbí ijinlẹ itẹlọrun bayii? Mo ní ìgbàgbọ pé o jẹ ohùn tí o fẹ láti máa ṣe ni, ìdí èyí ní o fí nyìn Ọlọrun nígbà gbogbo. Nígbàtí a bá ńṣe àfiwé tí a sì ńṣaroye, o túmọ sí a ńfa itẹlọrun tu ní o jẹ. Sibẹ ìdákéjì rẹ jẹ otitọ pẹlu. Bí a bá ṣe nyìn Ọlọrun tí a sì ńjọsin fún ùn, bẹẹnáà ní a o tubọ máa ṣafẹri Rẹ̀ síi. Bí a bá sì ṣe ndupẹ lọwọ Rẹ̀ bẹẹ náà ní yíò ṣe mọ́wa lára láti máa dúpẹ síi. Bí a bá ṣe nfi ẹmi ì.àn sí, bẹẹ náà ní ìfẹ rẹ yíò máa gbilẹ sí ní ọkàn wa pẹlu. Diẹdiẹ ní yíò sí máà hàn síwa pe Oun ni Ọlọrun tí ó kún ojú òṣùwọn tí ó sí to fúnwa. Ní òdodo Òun jù tító lọ! Lẹhinna àwa yíò le sọ ohùn tí Dafidi sọ pẹlu ìdánilójú, a sì lè polongo pe " èmi kò naani ohunkóhun"

Kilode tí a kò gbìyànjú láti yin ẹlẹda wa fún bí iṣẹju marundinlogun lojojumọ fún ọjọ marun? A tún lè ṣe àkọsílẹ ìhùwàsí rẹ tí o ṣe òkùnfà idupẹ wa. Tàbí kí a lo orin ìjọsìn lati se igbedide iyin wa. Ọnà tí a gbé gbà ko ṣe pàtàkì bikòṣe pe kí a gbìyànju láti yín kí a sí wo ohùn tí yíò ṣẹlẹ nínú ẹmi wa.

Selah - T'ẹsẹ̀ Dúró Láti Ṣe Àṣàrò Ṣe o jẹ ẹnití o máa nfi ararẹ ṣe àfiwé ẹlòmíràn àti ẹnití o nfi ẹdun ọkan rẹ hàn nigbakugba bí? Kíni yíò ṣe rí fúnwa láti ní itẹlọrun pẹlu Jesu tí a sì sọ ni òdodo pe " èmi kò náà ni ohunkóhun?"

Àdúrà ÌyìnẸni Mímọ. A yin nyìn pe ẹyin nikan not o to, Ọlọrun tí o ni irẹpọ pẹlu wa. Ẹ kò náà ní ohunkóhun. Ẹ sí ṣe ìlérí fúnwa pe ẹyin yíò pèsè ohùn gbogbo tí a nílò. A jọsin fún yín nítorípé ẹyin ni ìní àti olupese wa. Ọdọ nyìn ni a ti rí itẹlọrun alafia tí o tayọ gbogbo òye enia nitori a tí rí dájú pé ẹyin ni oninurere ati Ọlọrun tí o fẹ wa. Ohun gbogbo ti a nílò, ọdọ rẹ láti rí wọn. A dupẹ pé a le simi lé yín nípa ààbò lọdọ yín nítorípé ẹyin ní ohùn gbogbo labey ìṣàkóso yin. A yín yin a sì jọsin fún fún yín gẹgẹbi ẹni Mímọ, ẹni tító Ọlọrun wa.

Orin Dafidi 16:5 "Oluwa, ẹyin nìkan ní ìní àti ago wa, ẹyìn dáàbò bò ìpín wa"

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 3Ọjọ́ 5

Nípa Ìpèsè yìí

The Extraordinary Power of Praise: A 5 Day Devotional From the Psalms

Àníyàn, ìfọ̀yà, ìdánìkanwà àti ìsoríkó tí dìde gidi gàn láàárín ọdún mélòó kan tó kọjá. Àwọn èrò ìmólárá wonyìí kìí ṣe tuntun si àwọn Onísáàmù. Àmó, wón kó láti tú àgbàrá ìyìn tó ṣàrà ọ̀tọ̀ jáde láti bórí. Ṣàwárí àṣírí láti fọkàn rẹ̀ balẹ̀ nínú àwọn ìfọkànsin yìí láti ìwé Orin Dáfídì.

More

A fé dúpẹ lówó ilé ìṣẹ́ Moody Publishers fún ìpèsè ètò yí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ́ lọ sí: https://www.moodypublishers.com/the-extraordinary-power-of-praise/