Àwọn Ìgbésẹ̀ Àkọ́kọ́Àpẹrẹ
KA
Ní àkókù, ó dàbí ẹni wípé èrò pọ̀ ju àwọn ènìyàn lọ. Gbogbo àwọn èrò yẹn á máa yí padà. Lóòótọ́, ó lè nira púpọ̀ láti tẹ̀lé.
Ìwò àṣà ti ó ń yì padà bẹ̀bẹ̀ ìbéèrè náà, "Kíni òtítọ́?"
Tí o bá máa tèlé Jésù, o máa nílò láti fi ídákòrò aíyé rẹ sí òtítọ́. Èyí ni ọ̀kan nínú àwọn kókó ti ó mú àwọn Krìstẹ́nì yàtọ̀ sí àwọn ènìyàn tí kò tèlé Jésù: a jọ̀wọ́ aíye wa láti gbé òtítọ́ tí ìwé mímọ́ jáde. Àwa kìí ṣe àwọn ènìyàn tí à ń fi èrò gbé; dípò à ń tiraka láti mú aiyé wa wá sí inú ètò pẹ̀lú ohun tí bíbélì ń kọ́.
Ọ̀nà kan ṣoṣo ló wà láti fi ṣe èyí:
Kà.
Fetí sílẹ̀.
Kẹ́kọ̀ọ́.
Tí a bá máa tẹ̀le Jésù, a ní láti di ọ̀màràn pẹ̀lú àwọn ẹ̀kọ́ ìwé mímọ́, lẹ́hìn náà kí a mú aiyẹ́ wa wá sí ìlànà pẹ̀lú ohun tí ó ń kọ́ wa. A ní láti gbé ní ìdáhùn sí òtítọ́ náà, kìí ṣe nípa fífi èsì sí àṣà.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
O ti pinnu láti tẹ̀lé Jésù, kí lo wá ku? Ètò yìí kì ń ṣe àlàyé tó kún rẹ́rẹ́ nípa gbogbo nǹkan tó níṣe pẹ̀lú ìpinnu náà, ṣùgbọ́n yóò ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti gbé àwọn ìgbésẹ̀ àkọ́kọ́.
More