Àwọn Ìgbésẹ̀ Àkọ́kọ́

Àwọn Ìgbésẹ̀ Àkọ́kọ́

Ọjọ́ 5

O ti pinnu láti tẹ̀lé Jésù, kí lo wá ku? Ètò yìí kì ń ṣe àlàyé tó kún rẹ́rẹ́ nípa gbogbo nǹkan tó níṣe pẹ̀lú ìpinnu náà, ṣùgbọ́n yóò ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti gbé àwọn ìgbésẹ̀ àkọ́kọ́.

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ SoCal Youth Ministries – AG fún pípèsè ètò yìí. Tó bá fẹ́ mọ̀ sí, jọ̀wọ́, lọ sórí: http://youth.socalnetwork.org
Nípa Akéde

Awọn Ètò tó Jẹmọ́ọ