Jesu fẹràn mi

Jesu fẹràn mi

Ọjọ́ 7

Tí ẹnìkan bá béèrè lọ́wọ́ rẹ pé, “Kí nì mo ní láti gbàgbọ láti lè jẹ́ Kristẹni?” Kí nì ó sọ? Olùṣọ́-àgùntàn tó jẹ akọròyìn tẹ́lẹ̀ lo ọ̀rọ̀ orin, “Jésù Fẹ Mi Mo Mọ Bẹ́ẹ̀, Bíbélì L’o Sọ Fún Mi” láti jẹ́ kí ìgbàgbọ yé ọ. Akọ̀wé John S. Dickerson ṣàlàyé àwọn ìgbàgbọ ti Kristẹni àti ìdí tí wọ́n ṣe pàtàkì.

A fé dúpẹ lówó ilé ìṣẹ́ Akéde Baker fún ìpèsè ètò yí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ́ lọ sí: https://bakerbookhouse.com/products/235847
Nípa Akéde