Ṣíṣe Okoòwò L'ọ́nà T'ẹ̀míÀpẹrẹ
Njé ọ tí gbo nípa ohun tó ṣẹlẹ̀ ni Almolonga, ní orílẹ̀-èdè Guatemala?
LÀNÀ a sòro lórí ohun tó túmò sí kí Olórun mú òrun wà sí ayé nípasẹ isẹ́ owó. Lónìí a máa rí bí ó ṣe rí láyìíká rẹ̀...
Almolonga, ní orílẹ̀-èdè Guatemala jé ìlú tí kò dáa rárá. Ọtí mímu, iṣé awo, ati aje wón gbòde kan. Abùku, ìpànìyàn, àti àwọn ìwà òdaràn mìíràn. Èwòn wón mérèèrin kún fún eléwòn, àti pé won máa máa n ko àwọn eléwòn sí àwọn ìlú mìíràn. Agbègbè tó ń dáko lo jé, àmọ́ ilé náà kò sọ èso.
O kú díẹ̀ kí wón pá alágbe kan, ọ tí dààmú. O ń wa ọ̀nà àbáyọ̀ lójú méjèèjì, ọ kúnlè ọ sí tún oko re, ayé e, ati ilé agbègbè náà yàsímímọ́ si Olọ́run. Àwọn àgbè ìyókù darapọ̀ mọ́ ọ̀ wọ́n si gbàdúrà pé kí Ọlọ́run ro ibùkún rèé Rè sórí ilẹ̀ tó dá bí pé wón tí gégún le.Wón gbàdúrà pé kí ilé kékeré wón dá bí Òrun (Mátíù 5:10).
Olúwa gbò àdùrá wón O sí idahun ní ònà tó yani lénu (Ẹ́kísódù 2:24-25). Àwọn ènìyàn Almolonga ko àwọn òrìṣà wón dànù. Wón dẹkùn láti máa lọ sí ilé ọtí mímú wón bèrè sí ní ló sí ilé ìjósìn. Òpò lára wón tí kíí ṣíṣe bèrè iṣé gidigidi. Òpò ìgbéyàwó ní ọ sàn, àwọn ọtá di ọrẹ.
Bi ọdún ń se gori ọdún,ilé ọtí àti ìyàrá oúnjẹ 36 Almolonga ní dín kù di méta. Òkòòkan lára àwọn èwòn mérèèrin ko ṣiṣé mó, a sí pé èyí tó gbèyìn ni “Gbangbon Ola.” Olórí àwọn Kristẹni àti àwọn olórí ìjọ gbàgbó pé 80% àwọn olùgbé ìlú náà ti di eléyìn Kristi.
Ọ̀kan lára àwọn àbájáde tó yani lénu jù lọ ṣẹlẹ̀ ní agbègbè àgbẹ̀. Fún ọdún, ìkórè èso ko ṣe dáadáa nítorí ile to gbẹ táútáú àti àìkáràmáásìkí iṣẹ́. Lọ́wọ́ yìí ilè náà máa ń so èso ìkórè méta ní ọdún kánkan. Àwọn àgbẹ̀ Almolonga máa ń ràn ọkọ̀ akẹ́rù èso mẹ́rin lọ sí ọjà lóṣooṣù. Sùgbón ní báyìí wọn a máa rán ọkọ̀ akẹ́rù ogójì lọ́sọ̀ọ̀sẹ̀. Àwọn àgbè máa sàn òpò owó fún okò akérù ti Mercedes nlá wón a sí ko ẹsẹ Bíbélì àti àwọn gbólóhùn Khristini sára okò náà.
Àwọn èso fúnrawón tí yàtọ. Awọn èso dàgbà si ìlọ́poméjì iwọn déédéé wón. Awọn Karọọti nigba-gbogbo dagba si iwọn apá ọkùnrin. Agricultural àgbè tí bè Almolonga wò láti ìlú Améríkà àti àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn, wón gbìyànjú láti lóyè bí wón se ni ìkórè ọdọọdun tí àwọn èso tọ́ tóbi jù bo se yé lọ. Àmọ́ wọ́n kò rí ohun tí wón ń retí.
Ọlọ́run wo ilẹ̀ wọn sàn.
Ǹjẹ́ o tilẹ̀ lérò wípé Olúwa bìkítà nípa ilẹ̀ oko rẹ pẹ̀lú?
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Mo gba irọ́ kan gbọ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún. Irọ́ yìí wọ́pọ̀ l'ágbo Krìstìẹ́nì. Mo gbàgbọ́ nínú ìyàtọ̀ láàrin ohun tí kò jẹ mọ́ ẹ̀sìn àti ohun-mímọ́. Èyí fà mí sẹ́hìn gidi. D'arapọ̀ mọ́ mi láti ṣe àgbéyẹ̀wò bi Ọlọ́run ṣe fẹ́ẹ́ fí okun ẹ̀mí kún wa láti mú Ọ̀run wá sínú Ayé yìí àti láti ṣe àṣeyọrí nínú okoòwò atí ìgbé-ayé. A ní ànfààní púpọ̀ láti la ipa nínú ayé ju àwọn "òjíṣẹ́ Ọlọ́run orí ìjọ" lọ, ìlànà Bíbélì yìí yíò fi bóo ti rìn hàn ọ́!
More