Bọ́ Sínú Ìgbésí Ayé Tó Ní Ìtumọ̀Àpẹrẹ
Póòlù pé àwon ará Gálátíà láti gbé ìgbé aiyé tó fí ìwà òlàwó àìmotara-eni-nìkan han nípa èyí tí ó yàtò sí ìgbésí aye àrankan. Òmìnira tí a tí gbà láti òdò Kristi kìí sé ìwé-àse èrò ìmòtara-eni nìkan, sùgbón dípò rè, ó jé àñfaani láti yin Olórun lógo àti láti sin àwon elòmíràn nínú ìfé (wo Gálátíà 5:13).
Á lè wo Jesu gégébí àpeere pípé bi énìkan tí lo ìgbé aiyé Rè nínú àìmotara-eni-nìkan. Nínú ìgbé aiyé Rè, Ó mo ìdíyelé isé ìríjú bí Ó tí so pé, "Baba mí, bí ó bá see sé jékí ago yí kojá lódò mi". Síbè a ríi pé Jesu nínú isé àìmotara-eni-nìkan tí ó ga jùlo gégébí ó tún sé sope, "kìí sé ìfé mí, sùgbón ìfé tire ní kì á sé". Ó kú kì àwa lè sé àwòkóse Rè.Ó kú kì á lè rán àwon elòmíràn lówó láti sé bákan náà(wo Matteu26:39).
Bí ó sé nñfi àdúrà bebe lódò Olúwa pé kì ó fí òtító òrò Rè hàn o nínú èyí tí yíò mú o sin àwon elòmíràn nínú ìfé. Ó lè rí ara rè ní àwon ipò tí ó fí lè sin àwon míràn nínú ilè ìjósìn tàbí ibi tí ó tí ñsisé. Ohúnkohún tí ó bá ñse, sé gbogbo rè gégébí fún ìfé àti òmìnira tí Ó tí fun o télè.
Chenaniah Darma ló kọ ọ́
Fún àlàyé síwájú síi nípa Ilé Eko C3, jọ̀wọ́ lọ sí: here.
Nípa Ìpèsè yìí
Kí ni kókó ìwàláàyè mi? Kí ni ǹkan tí a dá mi láti gbé ṣe? Kíni ètò Ọlọ́run fún mi? Wọ̀nyí ni àwọn ìbéèrè tí púpọ̀ nínú wa ma ń bèrè nígbà kan tàbí òmíràn ní ìgbésí ayé wa. Ìlépa wa ni láti ṣe ìtúpalẹ̀ ohun tí a nílò láti ṣe fún ipa àti láti ní ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè náà. Darapọ̀ mọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé ìwé gíga ti C3 bí wọ́n ti ń tan ìmọ́lẹ̀ sí kókó náà.
More