Bọ́ Sínú Ìgbésí Ayé Tó Ní Ìtumọ̀Àpẹrẹ
Títí di Ìgbà tí Ọwọ́ Rẹ Kò Tó'lẹ̀ Mọ́
Ìwòye Ṣe Kókó fún Ìgbésẹ̀ Sínú Érèdí Rẹ.
Ìsíkíẹ́lì 47 sọ nípa odò tí ó ṣàn jáde láti inú tẹ́ńpìlì, láti ibi mímọ́ jùlọ (wo Aísáyà 6:1-6). Ẹsẹ̀ Bíbélì yí lágbára ní bí ó ṣe fihàn pé tí a bá lépa ìwà mímọ́ Ọlọ́run, láì ṣiyèméjì a óò gba ìwòye fún èrèdi tí Ó ní fún wa.
Ṣùgbọ́n, bí ẹsẹ̀ Bíbélì náà ṣe fi hàn, a kò leè lu àlùyọ ní ìjókòó tẹtẹrẹ.
Ìsíkíẹ́lì la oríṣi ìpele mẹ́rin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ kọjá kí ó tó lè through four different levels before he is able to ríi. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà ni à ń bi Ọlọ́run kí Ó fi èrèdi wa hàn, ṣùgbọ́n a kì í lè lépa dójú àmì. Ìwòye tí Ìsíkíẹ́lì rí jẹ́ ti ìyè lẹ́kúnrẹ́rẹ́ nítorí ó sún mọ́ ìṣe mímọ́ Ọlọ́run (odò, wo Sáàmù 1:1-3). Dídágú àti ikú ni ó ma ń gbẹ̀yìn àwọn ohun tí ó ún ráre kiri (Ìsíkíẹ́lì 47:11).
Tí ó bá ń fẹ́ ìwòye tó là gaara àti èyí tó lè gbé èrèdi dúró, o nílò láti wọnú àjọṣepọ̀ pẹ̀lú Ọlọ́run tí yóò ré kọjá gbogbo ààlà rẹ. Nínú èyítí ó mù ọ́ di gbín, níbití ẹsẹ̀ kò ti tó'lẹ̀ agbègbè ìrọ̀rùn rẹ. Níbí yìí lo ó tí jọ̀wọ́ ìṣàkóso fún Ọlọ́run, Ẹnití yíò gbé ọ dé èrèdi rẹ tó kún fún ayé lẹ́kúnrẹ́rẹ́ dípò.
A kọọ láti ọwọ́ Candace Tossas
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Kí ni kókó ìwàláàyè mi? Kí ni ǹkan tí a dá mi láti gbé ṣe? Kíni ètò Ọlọ́run fún mi? Wọ̀nyí ni àwọn ìbéèrè tí púpọ̀ nínú wa ma ń bèrè nígbà kan tàbí òmíràn ní ìgbésí ayé wa. Ìlépa wa ni láti ṣe ìtúpalẹ̀ ohun tí a nílò láti ṣe fún ipa àti láti ní ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè náà. Darapọ̀ mọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé ìwé gíga ti C3 bí wọ́n ti ń tan ìmọ́lẹ̀ sí kókó náà.
More