Ṣíṣe Àkóso Àkókò N'ìlànà Ọlọ́runÀpẹrẹ
Ígbé ayé wà fún láti dánì mọ̀ bẹ́ẹ̀ a kò gbé ayé nítorí ìdánimọ̀
Ẹni tí a gbàgbọ́ pé a jẹ́ ní ó ńṣe atọ̀nà ohun tí à ńsé àti báwo ni a ṣe ní ìmọ̀lára nípa ohun tí à ńsé. Ọlọ̀run fẹ́ kí a lo àkókò wá láti ibi ìdánimọ̀ dípò fún ìdánimọ̀ kí a bàa lè ní ààbò tí ó dájú nínú Rẹ̀
Eléyìí nílò pé kí a ní ìyípòpàdá àwọn àṣàrò gẹ́gẹ́bí ìbátan sí ìdánimọ̀ wá:
- Àìdánilójú ìdàkéjì dánilójú
- Ìta ìdàkéjì inú
- Ìbátan ìdàkéjì pípé
Irọ́ tí àwọn aráyé ń pá ni pé ìdánimọ̀ wá kò dájú àti pé a lè pàdánù rẹ̀ tàbí kí ó yí padà nígbàkúùgbà.Ododo láti inú ọ̀rọ̀ Ọlọ́run wípé ìdánimọ̀ wá dájú nínú Kristi. Gẹ́gẹ́bí ìwé Gálátíà 3:26 tí sọ: "Nítorí ọmọ Ọlọ́run ní gbogbo yín nípa ìgbàgbọ́ nínú Kristi Jésù"
Irọ́ tí àwọn aráyé ńpá ní pé àwọn ohun tó wà láyìíká wá ní ó ńsé okùnfà ìdánimọ̀ wá--ìrírí wa ohun ìní wa, ipò tí a wà. Òtítọ́ tí ó wà nínú Bíbélì ní pé ohun tí ó wà nínú wa nípasẹ̀ Kristi ní ó ṣé pàtàkì. Kólósè 3:12 ṣe àjọpín wípé ìwà inú wa ní ó yẹ kó jẹ́ ẹwà tí ìta. “Nitorina, bí àyànfẹ́ Ọlọ́run, ẹni mímọ àti olufe, ẹ gbé ọkàn ìyọnu wọ̀, àánú, ìrèlè, ìwà pẹ̀lẹ́, sùúrù".
Irọ́ tí àwọn aráyé ńpá ní pé ìdánimọ̀ wá dá lórí àfiwébóyá a "dára sí" tàbí a "burú sí" jù àwọn tí ó wà ní àyíká wá lọ. Ṣùgbọ́n òtítọ́ láti inú ìwé mímọ ní pé ìdánimọ̀ wa jẹ pípé àti pé ìdájọ́ ayé àti àfiwé kò ní ìtumọ̀ sí Ọlọ́run. Ìwé Fílípì 2:3-4 sọ bayi pé: "Ẹ̀ mà ṣé fí ìjà tàbí ògo asán ṣé ohunkóhun:ṣùgbọ́n ní ìrẹ̀lẹ̀ ọkàn kí olúkúlùkù rò àwọn ẹlòmíràn sí ẹni tí ó sàn jù òun tìkára rẹ lọ, kí ẹ má sí wò ohun tirẹ̀, ṣùgbọ́n olukuluku ohun tí ẹlòmíràn".
Bí ó ṣé ń ronú nípa bawo ní ó ṣé ń lò àkókò rẹ̀, ńjẹ́ ó tí bọ́ sínú ìdẹkùn ìrònú wípé ìdánimọ̀ rẹ̀ kò dánilójú, ó jẹ́ tí ìta, tàbí èyí tí ó jẹ fí ara pẹ́?
Tí ó bá rí bẹ́ẹ̀, báwo ni ó ṣé lè yí ìrònú rẹ̀ padà nípa ìdánimọ̀ rẹ̀ àti kí ó bẹ̀rẹ̀ sí ṣé àṣàyàn nípa àkókò rẹ̀ nínú Ọlọ́run tí ó ní ààbò lọ́wọ́?
CONTEXTREQUEST Key: day_3 day_3Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Bá a ṣe máa ń lo àkókò wa lọ́nà tó bófin mu lè fa másùnmáwo nígbà tá a bá ń sapá láti "ṣàkóso" ìgbésí ayé wa nípasẹ̀ agbára àti ìkóra-ẹni-níjàánu. Ṣùgbọ́n Bíbélì sọ fún wa pé a máa ń ní àlàáfíà àti ìsinmi nígbà tá a bá gbẹ́kẹ̀ lé Ọlọ́run nípa àkókò wa. Nínú ìwéwèé ọjọ́ mẹ́fà yìí, wàá mọ bí ọ̀nà tí Ọlọ́run gbà ń lo àkókò rẹ ṣe lè mú kó o rí gbogbo ohun rere tó ní fún ọ gbà, títí kan ayọ̀ àti àlàáfíà Rẹ̀.
More