ỌLỌ́RUN + ÌLÉPA: Ọ̀nà Láti Gbé Ìlépa Kalẹ̀ Gẹ́gẹ́ Bí KristẹniÀpẹrẹ
Ojó Kíni: Ṣe o dáa láti ní lépa gégé bí Kristẹni?
O fé tẹ̀lé Olórun o tún fẹ ní ìlépa pèlú ètè. Àmó o ní ìdààmú pé ìlépa má dárí e kúrò ní ètò Olórun fún o. Torí náà, O ń máa kọminú bóyá pé, "Ṣe o dára láti ní ìlépa gégé Kristeni? Kíni òrò Olórun sò nípa bíi à tí lè ṣẹ èyí àti máa bá ìfé Rè lo?" Olórun ní òpò láti sò nípa ìlépa, sisétò tọkàntọkàn, àti ìríjú lónà réré ohun tí a tí fún wa
Ìdáhùn tó kúrú: ìlépa dára! Kódà Jésù ní ìlépa. Ọlọ́run fé kí a gbé ìgbé ayé tó ní ìtumò, kò kàn selè. Òdòdó òrò pé o ń béèrè àti wá ìfé Rè túmọ sí pé o fé se ayé dáadáa. Òrò Rè fé tánmólè sí bí o má ṣe gbé ìlépa tó tónà àti sún ọ láti ṣáṣeyọri pèlú wón.
Àmó, má ṣe retí láti rí àkọsílẹ̀ tàbí fọ́múlà ojútùú kíákíá fún gbígbé ìlépa kalè nínú Bíbélì. Tó bá rórùn tó béè, a lè kà ìtòlẹ́sẹẹsẹ náà, máákì rè kuro, àti máa bá Olórun sòrò nípa àwọn ètò wa láé. Kìí ṣe nípa titèlé àwọn òfin, o jé nípa ìbáṣepọ̀ pèlú Ení tó ṣèdá é pèlú àwon ẹbùn tó yàtọ àti àwọn láti lọ nd táléńtì láti lọ, Olórun fúnra Rè.
Ònà mìíràn láti lépa tó dára? Rìn gbéregbère kiri, ń jé kí ayé ṣẹlè sí e. Ronú nípa é. Njé èyíkéyìí ení pàtàkì inú Bíbélì kan jókòó láìse nǹkan nǹkan? Sure, wọn ní àwọn àṣìṣe wọn, àmó Mósè, Dáfídì, Sólómónì, Ésítérì, Rúùtù, Jóhànù, Póòlù, Jésù fúnra Rè ní ìlépa, àti won dìde lẹyìn náà pèlú okun àti ogbón Olórun. Ìwo náà fé ṣẹ bákan náà, ìgbésẹ kékeré kan àti ìgbàgbọ́ irolesese.
Gbàdúrà pèlú mi: Olúwa, Mo fé tèlé Yín, gbígbé ìlépa tó bá ìfé Yín mú kalè fún ayé mi. É ṣeun pé é ṣ'èdá mi pèlú àwon ẹbùn tó dá yàtọ àti àwọn táléńtì láti lọ fún ètè nlá Yín. Mo fé lọ síbi tí É ń lo. É jòwó É hàn mi bí wọn ṣe lépa ní ònà tí É fé. Mo nílo ogbón Yín lórí sisétò àti ètè kí n bá lè ìríjú ohun tí é tí fífún mil— àkókò mi, owó mi, isé mi, àwọn ìbáṣepọ̀ mi, ìlera mi—kété níbi tí mọ ọ wà. É sí ojú mi sí òtítọ Yín àti ràn mi lówó láti sún ori dé ọkàn mi dé owó mi. Ní orúkọ Jésù.!
Nípa Ìpèsè yìí
Ǹjẹ́ o dára láti ní ìlépa gégé bí Kristẹni? Báwo ní o ṣe lẹ̀ mọ̀ tí ìlépa rẹ bá wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run tàbí ara rẹ? Àti wípé báwo ni ìlépa Kristẹni ṣe rí ní pàtó? Nínú ètò kíkà ọlọ́jọ́ márùn-ún yìí, o máa ṣàwárí nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run láti rí ìtọ́sọ́nà lórí gbígbé ìlépa tó kún fún ore-ọ̀fẹ́ kalẹ̀!
More