ỌLỌ́RUN + ÌLÉPA: Ọ̀nà Láti Gbé Ìlépa Kalẹ̀ Gẹ́gẹ́ Bí KristẹniÀpẹrẹ
Ojó Kejì: Báwo ní o ṣe lè Mọ tí ìlépa rè bá ń ṣẹ̀wá látọ̀dọ̀ Olórun tàbí látódò rè?
O tí bèrè sí ní rí: láìsí ìlépa, o lè má rìn gbéregbère kiri ní ayé. Àwọn ìlépa tí Olórun darí dára gan. Àmó! Báwo ni o se lè mò pé wọn jé ìlépa tí Olórun darí àtipe wón kìí ṣe tí rè? Báwo ní o ṣe lè mọ ìyàtò? Èrù mbá ọ pé wa yàn àwọn ìlépa tí kò tónà!
Ṣe o mò ohun tó yàni lẹ́nu nípa Olórun? Àwọn ohun tó pò, àmó kí dárúkọ, O fé sáyé dára dára l'ẹgbẹ é. Tí o bá nímọ̀lára pé o tí sọnù níní ìlépa rè àti ètè, tàbí nínú yíyan láàrín ìpà ònà kan tàbí mìíràn, O fé kí o béèrè fún ìrànlọ́wọ́ lówó Òun—àti O féràn láti ṣe ìrànwó! Jákòbù sò fún wa pé, 'tí èyíkéyìí nínú yín bá ṣe àìní ọgbón, é jé kí o béèrè lówó Olórun, tón fi fúnni gbogbo pèlú òlàwó láìsí ègàn, àti a yóò fi fún " (Jákòbù 1:5 ESV).
O kò mò bóyá àwọn ètò rè dára láti lépa?
Ṣe ìwádìí ní òtẹ́ẹ̀le:
- Sí Òrò kí o wá Àwọn Ìwé Mímó tàbí àwọn ìtàn tó ṣe pàtó nínú Bíbélì ṣàrídájú ìlépa tí o ní lókàn. Ṣe ìlépa rè ni yíyèkooro tó bá Bíbélì mú? Se àwọn Ìwé Mímọ pàtó wà tó ṣàrídájú e?' 'Gbogbo Ìwé Mímó lọ ní èémí Ọlórun wọn sí ní èrè fún èkó, fún ìbániwí, fún ìtọ́ni, àti fún ìkọ́ni tí ó wà nínú òdodo gbogbo. (2 Tímótì 3:16 ESV).
- Béèrè lówó Rè! Gbàdúrà kí o sí béèrè lówó Olórun láti fi ònà Tó fe jé ki o lo hàn e. 'Mo máa fún é ní ìtóni àti kó é ní ònà tó yé kí o lọ; Mo máa gbà é nímòràn pèlú ojú ìfé Mi lórí e' (Orin Dáfídì 32:8 ESV).
- Bí àwọn òré tó fokàn tán tàbí àwọn adarí tó féràn Olórun fún gu ìtọ́ni. ' láìsí ìmọràn, àwọn ètò kùnà,àmó pèlú òpò agbaninímọ̀ràn, wọn ṣáṣeyọrí' (Ìwé Àwọn Òwe 15:22 ESV).
Rántí, kò sí ọ́múlà ojútùú onídan tó ń se hihú jáde ìlépa àyàfi Olórun fúnra E. Tí o bá dàbí ìdáhùn náà kò hàn kedere, má se jòwó sílè on't give up! Èyí lè jé ara ìlànà Tó fẹ jé kí o la kọjá. Bí a ń ṣe dúró, a yóò àtúntò àti múra tán fún ohun tó kan. Dúró dé ogbón Rè, àtipe Yóò fi fún ọ ní àsìkò Rè tó ṣe pípé!
Gbàdúrà pèlú mi: Olúwa, É ṣeun fún òrò Yín! Mo morìrì ìtónisónà Yín tó ṣe kedere àti ogbón. É jòwó é ràn mí lówó láti foyè mò ìyàtò láàrin àwọn ìlépa àti àwọn ètò tí a bí láti inú ìfé mi sí Yín tí ìfíwera rè yàtò sí gbogbo àwọn yòókù. É ràn mí lọ́wọ́ láti mò ohùn Yín, gbékèlé ìdarí Yín, àti wà Yín You above gbọgbo nǹkan mìíràn. Ní orúkọ Jésù' Àmín!
Nípa Ìpèsè yìí
Ǹjẹ́ o dára láti ní ìlépa gégé bí Kristẹni? Báwo ní o ṣe lẹ̀ mọ̀ tí ìlépa rẹ bá wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run tàbí ara rẹ? Àti wípé báwo ni ìlépa Kristẹni ṣe rí ní pàtó? Nínú ètò kíkà ọlọ́jọ́ márùn-ún yìí, o máa ṣàwárí nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run láti rí ìtọ́sọ́nà lórí gbígbé ìlépa tó kún fún ore-ọ̀fẹ́ kalẹ̀!
More