ỌLỌ́RUN + ÌLÉPA: Ọ̀nà Láti Gbé Ìlépa Kalẹ̀ Gẹ́gẹ́ Bí KristẹniÀpẹrẹ

GOD + GOALS: How To Set Goals As A Christian

Ọjọ́ 4 nínú 5

ỌJỌ́ KẸRIN: Báwo ní mo ṣe lè mú ìlépa mi ṣẹ láì mu ré kọjá ààlà ìfẹ́ Ọlọ́run?

O ń dúró lórí ìbèrè ìlà, o fé sa tó àwọn ìlépa tí Olórun darí, àti.... O ń jàyà. Èrù ń bá o láti gbé ìgbésẹ lórí àwọn ìlépa náà, fífi àkíyèsí lórí sisáṣeyọrí lórí wọn tó jé o edge Olórun kúrò nínú ìlànà náà. Báwo ni o sé lè fí afíyèsí w lórí Olórun àti sisáseyorì lórí àwọn ìlépa nígbà kànnà?

Lákókò, àwọn ìlépa tó tónà máa darí rè lorí àwọn ipá Ònà Rè, ní àwọn ònà Rè, kìí ṣe Kúrò lódò Rè.

Èkejì, O kò ní ní ìlépa tó máa ní etíkun níbè. Olórun fé jé kí o sopò mò Òun ní gbọgbo ìgbésẹ ònà, àtipe Òun yóò O máa se atọ́nà e. Nígbèyìn nígbèyìn, Òun ní ìlépa. Titèlé àwọn ète tó ní fún wa dà bí máàpù To ṣèdá. O mò ònà.

Gégé bí o má sé ṣẹ ìrìn àjò tó gùn, wà máa wò máàpù láti dájú pé òun forílé ònà tító. Ti o bá mókàn kúrò lórí ètò náà, o lè rí ara rè lorí òpópó tí no kò mò. Àmó, tún gbé dìde lékan síi, àti wà pàdà sórí ọnà! Olórun kò ṣe aájò nípa bóyá tàbí o kò ṣáṣeyọrí ìtèsíwájú pípé nínú ìlépa; O fé ọkàn rè. sísẹ̀-n-tẹ̀lé, ádùrá léyìn ádùrá, àsìkò léyìn àsìkò bí o ń ṣe ń wà, wa dúró lórí ọnà tó yé. Ìsomò pèlú Rè máa Mú ṣàkóso lórí e.

Gbàdúrà pèlú mi: Olúwa, ẹrù ń bà mi láti out lórí ìrìn ònà tí kìí ṣe tí Yin. É jòwó É fún mi ní èmí tí kìí ṣe tí ìbẹrù, àmó tí agbára, ìfé, àti ìkóra-ẹni-níjàánu (2 Tímótì 1:7). É ṣe fún máàpù—Òrò Yin—ati fún agbára ìlèse láti gbàdúrà tààrà sí Yin! É jòwó É ràn mí lówó láti fi àkíyèsí sí Yin bí ìlépa dípò àwọn àfọwọ́sí ẹlòmíràn, ìyìn, tàbí the fàájì máákì àwọn nǹkan kúrò lórí àkọsílẹ. Mo fé ṣiṣẹ́ kára fún Yín fún àwọn ìdí tó yé. É ṣeun pé E tómi sónà àti mímú sórí ìpá ọnà Yin! Ní Orúkọ Jésù. Àmín.

Ọjọ́ 3Ọjọ́ 5

Nípa Ìpèsè yìí

GOD + GOALS: How To Set Goals As A Christian

Ǹjẹ́ o dára láti ní ìlépa gégé bí Kristẹni? Báwo ní o ṣe lẹ̀ mọ̀ tí ìlépa rẹ bá wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run tàbí ara rẹ? Àti wípé báwo ni ìlépa Kristẹni ṣe rí ní pàtó? Nínú ètò kíkà ọlọ́jọ́ márùn-ún yìí, o máa ṣàwárí nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run láti rí ìtọ́sọ́nà lórí gbígbé ìlépa tó kún fún ore-ọ̀fẹ́ kalẹ̀!

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Cultivate What Matters fún ìpèsè ètò yíi. Fún àlàyé síi, jọ̀wọ́ lọsí: http://www.cultivatewhatmatters.com/youversion