ỌLỌ́RUN + ÌLÉPA: Ọ̀nà Láti Gbé Ìlépa Kalẹ̀ Gẹ́gẹ́ Bí KristẹniÀpẹrẹ

GOD + GOALS: How To Set Goals As A Christian

Ọjọ́ 5 nínú 5

ỌJỌ́ KÀRÚN: Tí n kò bá forí tìí dópin ńkọ́?

O ní àwọn ìlépa dára dára lókàn rè, àti pé o nígbàgbọ̀ pé Ọlọ́run máa darí rè. Àmó, tí o bá kùnà nkó? Erù mbà o pé o kò ní tè lé ìtọ́ni, o máa bà jé, àti wa jà Olórun kúlẹ̀.

Gbólóhùn òrò kan wà tó wópò tó kà, "O gbàgbọ́ pé òun lè ṣe o dé se." Òrò Olórun fí òtítọ tó jinlẹ̀, tón itúsílè, bó tí lé jé pé: o gbàgbó pé òun kò lè, torí náà Olórun se. O kò ní láti ṣe gbogbo, ọ̀ré mi. Olórun kan retí pé kí o jé pípé. Ìdí nìyẹn tí O fí rán Jésù láti gbà wá là—O túmọ̀ sí wípé a nílo Olùgbàlà láti jẹ́ òkun wá nígbà tí a mbà se ààrẹ, láti ṣe ìtọ́sọ́nà wa, láti fi ọ̀nà hàn wa, àti láti ìjìyà fún àwọn ẹ̀sè wa. Ìhìn Réré ohun ń lo mú ìlépa tí Olórun darí pò sí, o ń rán wá lówó láti nímólárá ìṣúnsi lati pàdà sórí ojú ònà nígbà tí a bá ṣubú. Níbi tí o í tí lẹ̀ se, Òun lè se. Òdòdó òrò, O tí ṣe télẹ̀ lórí ìgi àgbélèbú. Kò sí ohunyóhun ti o lè sáseyorì tàbí má ṣe àṣeyọrí e, Olórun tí sáseyorì ìṣẹgun parí parí lórí ikú fún ọ àti fún mi! Kò sí ìbàjẹ́ tí o tí lé se tí Òun kan lè ṣe sí ohun tó rẹwà.

Jé ká mú gbogbo rẹ̀ mọ́ra wọn:

  • Wá Ogbón Rè lórí àwọn ìlépa tí Olórun àti ṣíṣéto ológbón. O máa fi fún o!
  • Gbé ìgbésẹ ní ìgbàgbọ́, ni àwọn ìlépa tó tóbi àti àwọn ìlépa àti ìgbésẹ tí wọn dà bíi èyí tí kò ṣe pàtàkì.
  • Àti gbẹ́kẹ̀lẹ́ É lati dá òòrè ọfẹ Rè sórí rè ní òpò ìgbà tí o máa bà jé lójú ònà— nítorí wa bà jé! Àmó, tí àwọn ìlépa rè bá wa tóka sí Òun gan gan, o kò ní fó okò. Wa yípadà sí Í fún òkun àti ogbón, ní mimọ̀ o máa ṣe sáseyorì lórí àwọn ìlépa rè kò ṣe pàtàkì bí ìdí.

Gbàdúrà pèlú mi: Olúwa, irú ìrìn àjò onígboyà ní èyí tó jé nínú Òrò Yin tí fúnni ní èmí! É ràn mí lówó láti ṣe nǹkan nípa ohun tí mo ti kó láti ní púpò jù lọ, rán mi lówó láti ṣàjọpín Ìròyìn Ayò tí Jésù. É jé kí gbogbo ìlépa mi, èyí tó tóbi àti kékeré, darí mi sódò Yin. Àti àwọn ìgbà tí mo bá kosè, É rán mi létí òòrè-òfé Yin tó ń yí ayé ẹni pàdà. É jé kí oore-òré náà sún mi láti tèsíwájú láti gbé ìgbé ayé ètè Yin fún ayé mi! Ní Orúkọ Jésù. Àmín!

Ọjọ́ 4

Nípa Ìpèsè yìí

GOD + GOALS: How To Set Goals As A Christian

Ǹjẹ́ o dára láti ní ìlépa gégé bí Kristẹni? Báwo ní o ṣe lẹ̀ mọ̀ tí ìlépa rẹ bá wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run tàbí ara rẹ? Àti wípé báwo ni ìlépa Kristẹni ṣe rí ní pàtó? Nínú ètò kíkà ọlọ́jọ́ márùn-ún yìí, o máa ṣàwárí nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run láti rí ìtọ́sọ́nà lórí gbígbé ìlépa tó kún fún ore-ọ̀fẹ́ kalẹ̀!

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Cultivate What Matters fún ìpèsè ètò yíi. Fún àlàyé síi, jọ̀wọ́ lọsí: http://www.cultivatewhatmatters.com/youversion