Mat 22:36-40

Mat 22:36-40 YBCV

Olukọni, ewo li aṣẹ nla ninu ofin? Jesu si wi fun u pe, Ki iwọ ki o fi gbogbo àiya rẹ, ati gbogbo ọkàn rẹ, ati gbogbo inu rẹ, fẹ́ Ọlọrun Oluwa rẹ. Eyi li ekini ati ofin nla. Ekeji si dabi rẹ̀, Iwọ fẹ ọmọnikeji rẹ bi ara rẹ. Ninu awọn ofin mejeji yi ni gbogbo ofin ati wolĩ rọ̀ mọ́.

Àwọn fídíò fún Mat 22:36-40

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Mat 22:36-40

Mat 22:36-40 - Olukọni, ewo li aṣẹ nla ninu ofin?
Jesu si wi fun u pe, Ki iwọ ki o fi gbogbo àiya rẹ, ati gbogbo ọkàn rẹ, ati gbogbo inu rẹ, fẹ́ Ọlọrun Oluwa rẹ.
Eyi li ekini ati ofin nla.
Ekeji si dabi rẹ̀, Iwọ fẹ ọmọnikeji rẹ bi ara rẹ.
Ninu awọn ofin mejeji yi ni gbogbo ofin ati wolĩ rọ̀ mọ́.Mat 22:36-40 - Olukọni, ewo li aṣẹ nla ninu ofin?

Ninu awọn ofin mejeji yi ni gbogbo ofin ati wolĩ rọ̀ mọ́.

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Mat 22:36-40