Gbogbo Ìṣísẹ̀ Ńy'ọrí SíbìkanÀpẹrẹ

Every Step An Arrival

Ọjọ́ 3 nínú 5

Ìṣẹ́ Àdámọ̀ Tí Ẹ̀mí

Nígbàtí nkán bá ṣẹlẹ̀ tí à kò lé ṣe àlàyé rẹ̀, àó pé ní ìṣẹ́ ìyànú. Lábẹ́ ìtúmọ wọnyi, ọ̀pọ̀ òhún tí alálupàyidà bà ṣe ní ńgo kà sí iṣẹ ìyànú, mò sì mọ̀ dáadáa wípé kò jẹ́ bẹ́ẹ̀. Ìṣẹ́ ìyànú, nínú àtọ́wọ́dọ́wọ́ tí bíbélì, kìí ṣe ohún tí kò ye wà bí kòṣe ohún tí a kò lé dá ṣe fún àrà wa. Ìyànú tí ó tún nkàn ṣe. Ohún tí Ọlọ́run ṣe fún wà tàbí tí Ó rán ẹ̀lòmiràn tí a kò lé ṣe fún àrà wà.

O ṣeéṣe kí ó yé ọ, ṣùgbọ́n botílẹ̀ ye ọ, kò báà wí wípé iṣẹ́ ìyànú ni. Ọ̀rọ̀ náà ò jàsí pé ohún tí o ju òye wa lọ bíì ohún tí o jù agbára wà lọ̀. Nígbàtí mo bá rìn jáde l'owurọ tí mo ri oòrùn tí o nyọ́ jáde, mo lè wípé, “Ìṣẹ́ ìyànú nìyẹn.” Àti pé èmi yóò jẹ̀ deede bíbélì. Àràárọ̀ jẹ́ ìṣẹ́ ìyànú.

Nítoríná báwo ni ìwọ́ à ṣe ṣ'àdojukọ láti rí iṣẹ́ ìyànú tí ojojúmọ́? Báwo ni iwọ́ à ṣe kó ara ní ijanu láti k'ẹ̀hìn sí ariwo-ọ́ja ilé ayé, kí o ba lè gbọ́ angẹ́li tí nkọrin àdidùn si ogó Ọlọ́run lóke to ga jùlọ?

O le fùn ní àkíyèsí rẹ, akiyesi ọ́pọ́lọ́ rẹ, iwarìri rẹ, ati òye rẹ. Gbigbọ́ kìí ṣe iṣẹ́ ẹran ara nìkan; o jẹ́ ọ̀gbọ́n-ẹmi ti inu ọkàn wa.

Má jẹ̀ kí ọ́mọ́ ìnú ibùjẹ́ ẹran tàn ọ. Ọmọ ọwọ́ ni, ṣùgbọ́n láti ìdile wòlíì Móse Ó sì ńbá ọ s'ọ̀rọ̀ lóni. O ńsọ ohún tí à ti ṣètò rẹ láti dàri àye rẹ, láti sìn ọ sí ìgbé ayé titun, ohún tí yíò rù ìdáhùn tí o ni àwọn ìwọn ayérayé. O wípé Olọ́run n'ifẹ rẹ, wípé Olọrùn gbà ọ, wípé ayé rẹ ni ìtumọ ayérayé oún ayànmọ́.

Njẹ́ mo gbọ́ tí o wípé o tí gbọ́ gbógbó ìyẹ́n rí? Rara o, ohún jẹ́ ọ̀rọ̀ tó r'ẹ̀wà títún to gbilẹ̀ ti o sì m'orí yá. Pàtó ti o bá gbọ, iwọ̀ kò tún gbọ́ ọ̀rọ̀ atíjọ́ mọ́. Ohún gbógbo di ọ̀tún. Ìrúfẹ́ ohún tí yíò mà dún l'ọ́tùn nígbà gbógbo ti à ba ńgbọ̀.

Kínní nkán kàn ti iwọ lé ṣe lóní láti darí ọ́kan àti ẹ̀mí rẹ sí ìyànú pé Ọlọ́run wà nínú ayé rẹ́?

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 2Ọjọ́ 4

Nípa Ìpèsè yìí

Every Step An Arrival

A lérò wípé àwọn ẹ̀kọ́ àṣàrò márùn-ún tí a t'ọwọ́ Eugene Peterson kọ yìí máa mú àyà àti ọkàn rẹ lọ síbi ti o fẹ́, nítorí a kò mọ ǹkan tí Ẹ̀míi nì ma lò láti gbani níyànjú, peni níjà, tàbí tuni nínú. O lè yàn láti lo àwọn ìbéèrè tó wà ní ìparí ẹ̀kọ́ àṣàrò kààǹkan láti ṣe àkòrí àdúrà rẹ fún ọjọ́ náà — kìíṣe ṣe gẹ́gẹ́bí ìparí ṣùgbọ́n bíi ìbẹ̀rẹ̀ fún àwọn ìbùkún tí a ti ṣètò sílẹ̀ fún ọ.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ WaterBrook Multnomah fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ́ lọ sí https://waterbrookmultnomah.com/books/540871/every-step-an-arrival-by-eugene-h-peterson/