Aláìjuwọ́sílẹ̀ Pèlú Lisa Bevere Àpẹrẹ
Olórun ñ so fún o, “Ìwo ní aláìjuwọ́sílẹ̀ Mi.” Kò se pàtàkì tí o kò bá nímòlára aláìjuwọ́sílẹ̀ nísinsìnyí; a tí pé o sínú isé Kristi tí kò lè parun. Tétí sí lara àwon ohun tí Olórun ñ so sórí è lónìí:
Ìwo ní aláìjuwọ́sílẹ̀ Mi, fìdímúlẹ̀ gbọn-in síbè ọlọ́kàn ṣíṣísílẹ̀—àwon ènìyàn wò è wón rí Kristi.
Ìwo ní aláìjuwọ́sílẹ̀ Mi—Èmí Kristi ñ gbè inú rè láti mú o dúró láìyẹsẹ̀ àti fẹsẹ̀ múlẹ̀ ṣinṣin.
Ìwo ní aláìjuwọ́sílẹ̀ Mi—ó ní èmí iná!
Jésù wá láti se ìrìbọmi wa pèlú Èmí Mímó àti pèlú iná. Èyí ní ìrìbọmi tí a gbódò gbà. Nígbà tí a bá tí dí àtúnbí,àwon okàn wa tón jé aláìlémìí tí wà lákọ̀tun látówó ìmólè oníná tí ifé ifé ayérayé Rè.
Ó kò mò ohun tí o dá bí nínú èmí. Ó rò pé o nko so òrò lasan, àmó ó ñ so iná! Ó ñ so àwon ohun tó pín ìmólè àti òtító niyà pèlú àwon iró òtá tó tí wá lórí àwon ènìyàn fún ojó tí pipé. Ó ñ so iná tón yó àwon sekésekè. Ó ní láti dúró nínú òtító yìí.
Èbùn tó mbé lórí ayé rè dá bí iná. Má se jé kí jó kú. Mí èmí lórí eyín iná àti fẹ̀ bí abẹ̀bẹ̀ sí ìléru ńlá gàgàrà! Àwon èlomìíràn ní-lò iná to jó mólè nínú rèti láti òdò rè, nítorí omo Rè ni e, a tí tún o bí lâti èdá Rè.
Olórun ñ bá e sòrò bí ó má see as you will become, kì i se bí o se wà. Ó ní ìgbàgbọ́ púpò nínú His ètò Rè fún ayé rè.Pẹ̀lú òye yìí, kí ni àwon ohun tó ní láti dékun (tàbí bèrè)láti máa sò sórí ara rè?
Tó bá gbádùn kíkà ètò kíkà yìí, mo gbà ẹ́ níyànjú pé óo lonlbjinlè sí nípa siṣàyẹ̀wò ìwé tuntun mi Adamant: Finding Truth in a Universe of Opinions.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Kíni òtítọ́? Àṣà ń gba irọ́ náà wọlé pé òtítọ́ jẹ́ odò, tó ńru tó sì ń ṣàn lọ pẹ̀lú àkókò. Ṣùgbọ́n òtítọ́ kìí ṣe odò-àpáta ni. Nínú rírú-omi òkun àwọn èrò tó fẹ́ bòwá mọ́lẹ̀, ètò yìí yóò rán ìdákọ̀ró-okàn wa lọ́wọ́ láti lè múlẹ̀-yóò sì fún ọ ní ìtọ́sọ́nà tó yanjú nínú rúkè-rúdò ayé.
More