Aláìjuwọ́sílẹ̀ Pèlú Lisa Bevere Àpẹrẹ

Adamant With Lisa Bevere

Ọjọ́ 4 nínú 6

Sé o fé jé gbajúmọ̀ . . . tàbí o fé lókìkí?

Ó dàbí ẹni pé gbígbajúmọ̀ àti ninípa lórí fé jo ara wón, àmó wón yàtó gidi. Gbígbajúmọ̀ ń fẹ́ kí o tè lé òpò ènìyàn tàbí so fún wón ohun tí wón fé gbò. Àmó ninípa lórí pè ó láti dúró lórí òtító jìnnà sí ogunlọ́gọ̀ àwọn ènìyan.

Látòkèdélẹ̀, òtító kì í see kí ni, àmó tani, nítorí Jésù so pé Òun ni òtító. Jésù tún so pé Òrò Olórun òtító ní. Ayé fé láti ronú òtító bí ìlọsókè-sódò àti rorùn, àmó a tí fidí òtító múlè ní ènì Jésù àtipe Òrò Olórun kò yí padà láéláé. Nínú ayé tó kún fún èrò, òtító Olórun samònà wa sí ìdánilójú tí a lè kó ayé wá le lórí.

A gbódò sóra láti fòye mò ìyàtọ̀ tó wà láàárín àwon èrò àti àwon ìdánilójú. Ayé yí kò ní-lò ìdọ̀tí tó wá pèlú òpò èrò. O ní-lò ìwàdéédéé tó wá pèlú òtító. E má se jé kí a ṣètìlẹyìn sí ariwo tó pín okàn níyà àti fà wa séyìn kúrò nínú wiwò àwon Ìwé Mímó àti Èmí òtító.

Àwon èrò rorùn láti se àti yára láti yí padà,àmọ́ wón le láti palè mò tí a bá jé aláìbìkítà ní titàn tí wa kálẹ̀ kárí. Wón lè dá bí ìdọ̀tí tó fa ègbin sí ayé àwọn ẹlòmíràn àti awa náà. A gbọ́dọ̀ bìkítà gidigan láti máa se èsó àwon òrò wa láti rí i dájú pé a jé ara ojútùú sí àwon ìsòro tí a tá àmì òróró lewa láti yí padà.

Mo pè o nijà láti ṣàtúnṣe ayé rè àti ṣàtúnṣe àwon òrò tí a yàn láti so. Má sóra nípa ohun tó kà, féti sí, wí, tàbí firánsè. Má se gbé awuyewuye ìdílé rè sí aféfé, tàbí awuyewuye tí soosi, fún gbogbo ayé láti rí. Síbè, nígbà nan náà, má se dákẹ́ nípa wón: Bá èbi sòrò nípa awuyewuye ebí .Tí ènìkan kò bá lówó nínú ìsòro tàbí ojútùú, má se jé kí wón lówó sí láìnídíì. Èyí má mú ìsòro náà tóbi sí dípò kí o wá ojútùú sí.

Báwo ní didákẹ́ nípa àwon awuyewuye tó se pàtàkì se jé kan naa sí fifowó sí wón? Kí ní o túmọ̀ sí láti ṣàtúnṣe àwon òrò rè ní ònà tó jé pé o jé ara ojútùú àti kì i se ara ìsòro náà?

Ọjọ́ 3Ọjọ́ 5

Nípa Ìpèsè yìí

Adamant With Lisa Bevere

Kíni òtítọ́? Àṣà ń gba irọ́ náà wọlé pé òtítọ́ jẹ́ odò, tó ńru tó sì ń ṣàn lọ pẹ̀lú àkókò. Ṣùgbọ́n òtítọ́ kìí ṣe odò-àpáta ni. Nínú rírú-omi òkun àwọn èrò tó fẹ́ bòwá mọ́lẹ̀, ètò yìí yóò rán ìdákọ̀ró-okàn wa lọ́wọ́ láti lè múlẹ̀-yóò sì fún ọ ní ìtọ́sọ́nà tó yanjú nínú rúkè-rúdò ayé.

More

A fé láti dúpé lówó John àti Lisa Bevere fún pipèsè ètò yìí. Fún ìsọfúnni sí i, E jòó ṣèbẹ̀wò: http://iamadamant.com