Aláìjuwọ́sílẹ̀ Pèlú Lisa Bevere Àpẹrẹ
Ṣọ́ọ̀ṣì sábà maa ń yára láti dẹ́bi fún àwọn aláìgbàgbọ́ fún èsè àti ìhùwà wón,síbè kó yé kò yà wá lénu pé àwon ènìyàn tí kò mò Olórun hùwà bé ní pe wón kò mò Olórun. Ohun tí o yé kí a bìkítà ara wá pèlú,lákọ̀ọ́kọ́ ná, ní bóyá a ń gbé ìgbésí ayé mímó àti èyí tó yípadà.Bí tí tò Olúwa, à lè béèrè fún ọgbọ́n nígbà náà láti fi inú rere Rè hàn sí ayé tó yí wá ká ní ònà tó pè wón láti wá ìyípadà wón nínú Rè.
Gégé bí àwon omo Olórun, a tí tún wá dá nínú Kristi láti dá bí dáyámọ́ńdì sìbé jé pẹ̀lẹ́tù bí òdòdó.
A ń gbé nínú ayé tó se ìmúse ohun tí Pọ́ọ̀lù kòwé ní Róòmù 1.Òpò lara wa lo tí fi ìmò àti wíwàníhìn-ín Olórun sílè àtipe wón kò lè mò ìhùmò Rè fún ẹ̀dá ènìyàn mó.
Àmó béèré lówó ara rè, se ikédàárò nípa àwon ibi ojó wa yí ohunkohun pa dà?Ó baní nínú jé pé, a ti mò wa fún ohun tí a lòdì sí jù ohun tí a wá fún lo. Ìjémímó àti àyípadà tí a wá nínú àsà wá kò ní wá nípasè didẹ́bi fún àti bibẹnu àtẹ́ lu ohun, àmó nígbà tí a bá dáhùn awuyewuye tí ara wa kákọ̀ọ́kọ́ náà, àti léyìn náà ìtúsílẹ̀ inú rere Olórun, àánú, àti ìrètí sí àwon tó ní-lò è.
God's Inú rere Olórun nígbà gbogbo jé Ìkésíni fún wa láti padà sí òdodo, dípò sí ìfowó sí èsè. Ìdí nìyí tí a ní-lò ọgbọ́n.Nígbà mìíràn, a se bé ní pé o dára láti so pé èsè kì í see èsè nítorí a kò fé kí ojú tí àwon ènìyàn. Àmọ́ ṣáá o,a ní láti máa pè èsè ní ohun tó jé, síbè se ní ònà tó má mú ìtúsílẹ̀ ìrètí dípò ìdalẹ́bi.
Ìjémímó ní àsà wa béré pèlú fifún Olórun ni gbogbo ara wa pátá. Ìran kan mbé tó nílò àyípadà gidigidi, àtipe wón dúró láti rí nínú wa.
Olórun so pè Òun yóò wo ilè wá sàn nígbà tí àwon ènìyàn Rè bá rẹ ara awọn sílẹ̀, tí wọ́n bá sì gbàdúrà, kì i see nígbà tí gbogbo nñkan bá wà lọ́wọ̀ọ̀wọ́ lọ́nà pípé ní ìjoba ilè náà.Kí ni èyí túmò sí fún o?
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Kíni òtítọ́? Àṣà ń gba irọ́ náà wọlé pé òtítọ́ jẹ́ odò, tó ńru tó sì ń ṣàn lọ pẹ̀lú àkókò. Ṣùgbọ́n òtítọ́ kìí ṣe odò-àpáta ni. Nínú rírú-omi òkun àwọn èrò tó fẹ́ bòwá mọ́lẹ̀, ètò yìí yóò rán ìdákọ̀ró-okàn wa lọ́wọ́ láti lè múlẹ̀-yóò sì fún ọ ní ìtọ́sọ́nà tó yanjú nínú rúkè-rúdò ayé.
More