Aláìjuwọ́sílẹ̀ Pèlú Lisa Bevere Àpẹrẹ

Adamant With Lisa Bevere

Ọjọ́ 2 nínú 6

Kò sí ènì tó ń dàgbà láìsí ìfówo kan òkùnkùn. Gbogbo wa ló ń gbọ́ àwon ohùn láyìíká wa dé àyé kan, tó ń dá wa léjó àti pè wa lórúko. Òpò, tí kì i bá se gbogbo wa, tí fún ara wa lórúko bákan náà—àwon ìdánimò èké tí a lè búra pè wón jé òtító.

Nígbà tí Olórun bá sún mó wa, kì i se láti dá wa lébí, àmó láti kówa jọ mora tímọ́tímọ́ si ara Rè kí a bá lè gbò ohùn Rè tón polongo òtító ènì tí a jé gan-an.

Òtító ní: A kì i se òkùnkùn tí ìgbà wa tó ti ṣẹlẹ̀ kọjá. Àtipe a kì í ṣe àwon àsisè wa, ọkùnrin tàbí obìnrin, tàbí ohunkóhun tí òde ara. Dípò, èmí ní wa tí a sèdá ní àwòrán Olórun, tí a hùmọ̀ fún àjosepò tímótímó pèlú Ènì tó fún wa ní èémí.

A gbójú fo ìdánímó wa nígbà tí a bá so mó àwon ohun tí kò tònà. Ìdi niyi tí Olórun máa fi bó àwon lébẹ́ẹ̀lì tó pààlà tí a gbà lójú ònà kúrò. Èmí Rè sisé nínú wa,ñ yo ohun tí ogbó kúrò àti hú jáde èyí tí a lè rí.

Bóyá ìbẹ̀rù àti àìsí ìfọ̀kànbalẹ̀ tí mú o ko isé Olórun sílè nínú ayé rè. Àmó lónìí, Olórun ñ sòrò si àwon ibi tí o ró pé wón dahoro, àtipe Ó ñ se pèsè láti tún yí wón padà si ogbà.

Àmó a ní láti múra tán láti jé kí Olórun yo ìmọ́lẹ̀ kúrò nínú òkúnkún nínú ayé wa. Olórun kò ní fún àwon iró láàyè láti dúró. Kò ní fún àwon ohun tó sò sórí ara rè láàyè láti jé ìpinnu ìkeyìn. Dípò, Ó máa sún mó e kí O lè tímótímó fi ohun tuntun hàn nínú rè, ohun tó mú ìwòsàn pátápátá wa sí gbogbo agbègbè ìrora, tón sọ ó dòmìnira láti gbè nínú òtító énì Tó ní o jé.

Olórun jé aláìjuwọ́sílẹ̀ tímótímó. Ó máa lo si àárín ìrora rè láti wo o sàn nínú àìlera náà, àmó o gbódò fún láàyè láti se èyí. Kí ni èyí lè dà bí nínú ayé rè?

Ọjọ́ 1Ọjọ́ 3

Nípa Ìpèsè yìí

Adamant With Lisa Bevere

Kíni òtítọ́? Àṣà ń gba irọ́ náà wọlé pé òtítọ́ jẹ́ odò, tó ńru tó sì ń ṣàn lọ pẹ̀lú àkókò. Ṣùgbọ́n òtítọ́ kìí ṣe odò-àpáta ni. Nínú rírú-omi òkun àwọn èrò tó fẹ́ bòwá mọ́lẹ̀, ètò yìí yóò rán ìdákọ̀ró-okàn wa lọ́wọ́ láti lè múlẹ̀-yóò sì fún ọ ní ìtọ́sọ́nà tó yanjú nínú rúkè-rúdò ayé.

More

A fé láti dúpé lówó John àti Lisa Bevere fún pipèsè ètò yìí. Fún ìsọfúnni sí i, E jòó ṣèbẹ̀wò: http://iamadamant.com