Aláìjuwọ́sílẹ̀ Pèlú Lisa Bevere Àpẹrẹ
Nígbà tí a bá gbà ifé Olórun, ìdáhùnpadà tó dára jù lo àti tó pondandan ní fún wa láti fún àwon mìíràn ní ifé. Ó yé kí a nífèé láìbèrù, tayọ̀tayọ̀, àti títí ayérayé. Èrí òtító tí ènìyàn tó mò pé wón nifèé òun ní wipé wón nífèé dáradára.
Olórun kò ní ifé; Òun ní ifé. Ifé ní èdá Rè gan-an. Àtipe nítórí Ifé ní Olórun, o kò lè di I lówó láti féràn è. Ìfé Rè kò seé ségun àti o fẹsẹ̀ múlẹ̀ gbọn-ingbọn-in, o dúró láìyẹsẹ̀ pèlú gbogbo ajórèyìn àti àlèébù rè.
Sùgbón nítórí Olórun féràn gbogbo ènìyàn, Òun kò lè féràn gbogbo nñkan. Níwòn bí Olórun jé aláìjuwọ́sílẹ̀ nínú ifé, O gbódò jé nínú aláìjuwọ́sílẹ̀ nínú ìkorira.
Èyí lè dà bí ìtakora tá bá kókó wò, àmó èyí nítorí àsà wa tí so ifé dí òrìsà. A mò pé Olórun ifé ni, àmó se a tí so èrò wa tí ifé dí olórun?
Òtító ni, Olórun korira ohun tó bá ṣàyípadà ifé. O korira ohun to ya àwon Tó féràn sọ́tọ̀. Ìdí nìyí tí Olórun gbódò korira ohun tó fa ìdàrúdàpọ̀ sí ìdánimọ̀ wa.
A kò lè ní ojúlówó ifé tí a bá “ féràn gbogbo nñkan.” Olórun jé aláìjuwọ́sílẹ̀ nínú ìfé àti ìkorira, so a gbódò kó láti féràn ohun tí Olórun féràn àti korira ohun tí Olórun korira.
Kí ni àwon ònà tí àsà tí soèrò è tí ìfé í olórun? Olórun féràn gbogbo ènìyàn, àmó Kò féràn gbogbo nñkan Kí ni òtító dà bí ní ayé rè ?
Nípa Ìpèsè yìí
Kíni òtítọ́? Àṣà ń gba irọ́ náà wọlé pé òtítọ́ jẹ́ odò, tó ńru tó sì ń ṣàn lọ pẹ̀lú àkókò. Ṣùgbọ́n òtítọ́ kìí ṣe odò-àpáta ni. Nínú rírú-omi òkun àwọn èrò tó fẹ́ bòwá mọ́lẹ̀, ètò yìí yóò rán ìdákọ̀ró-okàn wa lọ́wọ́ láti lè múlẹ̀-yóò sì fún ọ ní ìtọ́sọ́nà tó yanjú nínú rúkè-rúdò ayé.
More