Ètò Ìjàkadì Ogun Jíjà Tí ÈmíÀpẹrẹ
OJÓ 5: Àwọn Ònà Méje Láti Mú Kí Esu Sa Jáde
Olórun tí ṣèlérí fún wa pé Òun yóò mú wá bórí kí àwọn òtá wa tó dìde lòdì sí wa láti pòfo níwájú wa. Àmó a lè dí ìbùkún wá lówó àti fààyè sílẹ̀ fún òtá láti dúró níwájú wa kàkà kí won sá lónà méje. Pèlú ìyen ní ọkàn rè, níhìn ní àwọn ète ọgbọ́n ẹ̀wẹ́ méje láti mú esù sá jáde lónà méje.
1. Faápọn ìgbọràn sí ohùn Olúwa Olórun re
2. Ìrònúpíwàdà kí o tó wọnú ìjàkadì
3. Mò wípé Olúwa mbè lẹyìn rẹ
4. Jágún láti ibi ipò ìṣégun
5. Máa yin Ọlórun láti jagún
6. Gbè ìhàmóra ogún rẹ wò
7. Máa gbàdúrà nígbàgbogbo àti kí o máa sọra
Fi fópin sí agbára idẹkùn ìká sábà máa ń jé nípa ṣiṣé ìpinnu tó dára, àmó tó bá jé idẹkùn èmí èsu o ní láti ṣe dánímò èrò àti àwọn èrò tí kọ totún àti ọna ìrònú tón gba àwọn èmí búburú láàyè láti ṣe jàmbá ní ayé e.
É jade lọ, èyín jagunjagun tèmí, pèlú ìyìn nínú ọkàn yín pèlú ádùrá lórí ètè yín, ní ìmúra fún ogun. Tí Olúwa ní ogun náà, àti pé èsu máa sá lo ní ònà méje. Kò ní ònà mìíràn nígbà tí a o bá jòwó ará e sílè fún Olórun àti térí ará rè bà níwájú Olórun dènà e. Kòsí èmí èṣù ti àpàádì tó lágbára jù ìfé tó wa nímúbáramu pèlú Òrò Olórun. Òòrè ọfẹ Olórun kún ọkàn tó ń kọ̀ọ́kọ́ wá ìjọba Ọlórun àti òdodo Rè.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Nipasẹ àwọn èkó tó lágbára wónyìí o máa ṣàwarí óye tó jinlẹ̀ lórí bí o máa se ṣèdá ogbón láti gbọn féfé ju àti borí àti sèdíwọ fún ètò òtá rè láti pá ayé è rún
More