Ètò Ìjàkadì Ogun Jíjà Tí ÈmíÀpẹrẹ

Spiritual Warfare Battle Plan

Ọjọ́ 3 nínú 5

ỌJÓ 3: Àwọn Ìmólárá Èké Ìbẹrù

Èrù bèrè sí ní jé àdììtù sí ọkàn mi nígbà tí mo wà ní ọmọde. Mo rántí dáadáa pé mo ń máa rí èmí ẹrù nínú iyàrá mi lópo ìgbà ní alé àti pé mo máa páriwo fún ìyá mi. Ìyá mi máa wọnú ìyára pèlú ìgbàlé láti lè jáde kúrò, mo ń rò pé o kàn jé òye ọkàn mi tí kò balè lọ n ṣiṣẹ. Àmó o sábà máa ń padà wá pèlú èsan.

Bí àgbàlagbà, léyìn ìgbà ti mo ti jìyà àwọn òpò ìṣẹlẹ adanilóri rú, èrù jọba lórí ayé mi. Èrò ìmólárá èké èrù kìí wá nṣe ìmólárá lasan. Mo ní àkójo àwọn èmí èrù tón ni ipa lórí gbogbo apa ayé mi wọn sí fará hàn ní orísirísi ònà.

Èrù jé májèlé sí é. O jé ohun ìjà agbára lówó ọtá tó tákò àwọn ìlérí Olórun nínú ayé e. Ìbèrù wa láti dà o dúró láti tèsíwájú nínú Olórun. Àmó o lè gbà òmìníra lówó odì agbára nínú ọkàn e. O lè lọ àṣẹ lórí èrù nígbà tí o bá gbìyànjú láti dìde lòdì sí ọkàn e.

Bàbá, ní orúkọ Jésù Mo to Yín wá ní ìrònú piwadà ní fifààyè gbà àwọn ìmólárá èrù. Mo bá èmí ìbèrù wí tón ṣiṣẹ láti dẹ mi sí páńpẹ́, jí ìgbàgbọ́ mi, jà mi lólè àlàáfíà mi, àti lónà kejì fí mi sí àdiìtù pèlú àníyàn, ní orúkọ Kristi. Mo yàn ìgbàgbọ́, igbékélè, àti ìfé. Olórun nìkan ni mọ féràn àti gbékélè, ni orúkọ Kristi. Àmín.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 2Ọjọ́ 4

Nípa Ìpèsè yìí

Spiritual Warfare Battle Plan

Nipasẹ àwọn èkó tó lágbára wónyìí o máa ṣàwarí óye tó jinlẹ̀ lórí bí o máa se ṣèdá ogbón láti gbọn féfé ju àti borí àti sèdíwọ fún ètò òtá rè láti pá ayé è rún

More

A yòó fé láti dúpe lówó Charisma House fún ìpèsè ètò yii. Fún ìsọfúnni síwájú sí, Jọ̀ọ́ bè eyii wò: http://bit.ly/spiritualwarfarebattleplan