Ètò Ìjàkadì Ogun Jíjà Tí ÈmíÀpẹrẹ
OJÓ 4: Pàkúté Ìkòrò
Mo ń se ọbẹ̀ nínú àwọn oníhílàhílo mi. Ọkọ mi tí pámi tí pèlú omo-odún éjì àti òpò of gbèsè kí o bá lè bèrè ayé tuntun pèlú obìnrin kàn tó jé ìdajì ọdún orí è ní orilẹ èdè àjòjì. Inú bími gan àti mọ fé gbésàn. Inú mi ru ṣùsù—àti pé kò nílò èbùn èmí ifoyèmò láti rí i. Mo kòrira e, inú bí mi si Olórun.
Ìkòrò lè sékú páni. Bí ojó ni se gorí ojó, ìkòrò máa fi ègbín sí èémí wa àti pa agbára wa láti nímòlárà ìwàláàyè Olórun tàbí gbò ohùn rè. Tí o mbá bínú sí Olórun, jé olóòótọ pèlú Rè. Fún Ùn ní ìbínú rè, Òun yóò sọ ìbínú náà di àlàáfíà àti ìsípaya aláṣẹ tí o bá máa gbà A láàyè.
Olúwa, mo pinnú lati dáríjì àwọn tó pámílara, tí wọn ṣè mi, se èébú si mi, tón lomi nílòkulò tàbí sáìtó simi Olúwa, É ràn mí lọ́wọ́ láti dá ìsètò otá láti fimo sí ìdẹkùn mò fún mi ní ìfìbínúhàn, ìkòrò, àti aìní ìdáríjì. É ràn mí lówó láti má ṣe mú àwọn èsè àwọn èèyàn dání lòdì sí wón. É kọ mi láti yẹra fún ìdáhùn pèlú ọkàn tó ń dání lébi nígbà tí mo bá ní ìpalára. É wón àwọn èrò ìmólárá mi sàn àti kí E ṣàyípadà èmí ọtún nínú mi. Ni Orúkọ Jésù, Amin.Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Nipasẹ àwọn èkó tó lágbára wónyìí o máa ṣàwarí óye tó jinlẹ̀ lórí bí o máa se ṣèdá ogbón láti gbọn féfé ju àti borí àti sèdíwọ fún ètò òtá rè láti pá ayé è rún
More